Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òtùrùpòn Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Gidigidi gbonbi ose Adifafun elelyi aponsin Nijo ti n lo bi oku ope Ebo ni won ni kose Osigbebio ni be orubo Nje gidiigidi gbonbi ose Ifa boba buru mapon Leyin ire ao toju eran otolo ao toju ewe aje ewe ire ewe omini ao wa fi se eran otolo yi lepo wi yo ao w ate iyere osun ni odun ifayi ao wa se adurasi ao wa je obe naa ni owuro aojo keji

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi ki elelyi orubo isegun kolo bo ifa pelu eran ewure kan pelu ije imu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran erure kan epo eko obi oti
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Yangin abori kugun Adifafun otolo beleye Nijo ti lole gbayin lari Eranko Ebon in won ni kose Osigbebo ni be orubo Nje ifa oto gege kigbayin Nile baba mi Gege bi otolo bleje se Gbayin lari eran ko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire iyin fun lelyi EBO ni ko se kio si lobo orire pelu pepeye kio sifi akuko adire meji rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye kan Akuko adire meji Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Orisa ika kotougbika Aro gunwon lobe Won a pon salo Adifafun sedigelete Ti se obinrin esu Igba timomi ojusogbere ire Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Eropo Ero ofa Ewa bani ni jebutu ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa p oun pe ire gbogbo fun elleyi EBO ni kose kio lobo esu pelu eran oruko ati oti oyinbo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Oti oyinbo Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Tubu ni yanrin Kere ni yangi Adifafun otolo beleje Ti se egbon ibaka Igbati won be nirogun ota Ebo ni won ni kiwon ose Won gbebo ni be won rubo Nje boba buru ototo beleye Oto gege kogbawo kuro win ibi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun fun elelyin ki elelyi olobo ifa pelu ewure kan kio si fi akuko adire rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Akuko adire Epo Eko Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ewe ologun sese ao toju atare ati ori kanko ao wa jo meteta papo ao wa fi sigbere si arin ori mokanlelogun ni gbere naa.

Videos

Watch Òtùrùpòn Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òtùrùpòn Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òtùrùpòn Ósà Odu.