Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Oturupon Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Oturupon Meji in Ifa Divination represents endurance, learning from past experiences, and the consequences of unchecked actions.
Listen
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oturupon-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Bimoseferin ni mo fe ki ore mi o ri Adifa fun olomon ateni ore kore Igba ti n tode orun bo waye Ebo ni won ni ko se O gbe bo ni be orubo Nje, eni timo wu oba loje Orisa jeni ti mowu owumi Eni ti mowuoba loje.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire iyin fun eleyi ki eleyin osibo orire nitori agbega kio si feran omo lakeji re gege bi tarare.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodie kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Bebe okehin Bebe oke ohun Adifa fun oturu Ti o pon meji lekan Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo nje igba oturupon meji lara ro awo. Ao toju erupe yaya ogan ao toju ewe awede ao wa mon ose dudu ao wa fi omi agbon po titi ti yio fii de ao wa mon fii we.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun ire omo fun eleyin pe oju omo nip on kolo boo sun pelu adire agada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie meji Akuko kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Akara ni ko kuta lojude opon Adifa fun ayinrin Ti se omo won lojude iwoya Igba ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo ni be orubo Nje oni apa ayinrin Ola apa ayinrin A le pa ayinrin mon tuntun la n tu ayinrin.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin orubo isegun pe awo kan ni won gbo ti eleyin ebo ni kose.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Pepe lawole Atita lawo ode alapanu dede Lokole tan lokoju re si gbagede olofin Beni kofin kan omi beni ko fi kan oke Adifa fun oyepolu Ti se omo isoro nife Baba re ku O fi sile ni leunje leunje Iya re ku ofi sile ni lenje lenje Won wa ko ohun oro le O bu puru sekun Ebo ni won ni ko se O gbebo nibe orubo Nje epo ni won koko tale Emi omon isoro orun E ya wa gba oro ta se Omi oti eku eja eye eran ni won ko si lele Emi omon isoro orun Eya wa gba oro ta se.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyin orubo isegun ki osi lobo awon olorun re dara dara kio si rubo pe ohun yio ba segun ki osi lo bo ifa pelu eku eja adire eran ewure.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodie kan Ewure kan Epo Eko Obi Oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao mu ewe segun sete pelu ewe alupaida ao gun mon ose dudu ao wa fi maa we fun ojo meje. AWURE

Videos

Watch Oturupon Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Oturupon Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Òtùrùpòn Ogbè, Òtùrùpòn Òyèkù, Òtùrùpòn Iwòrì, Òtùrùpòn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oturupon Meji Odu.