O
This Odu signifies the power of patience and strategic planning in achieving success.
Read This Odu in Other Languages
Verse-level switching (Yoruba, English, Spanish, Portuguese, French) is available directly inside each verse below.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Orobo topo
Adifafun ogo
Tii se omo kuurin soku
Igba ti n momi oju sogbere aje
Adifafun ogo
Tii se omo kuurin soku
Igba ti n momi oju sogbere aje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi
ki elelyi olobo ifa pelu pepeye
kan kio sib o ori re pelu agbon
ki elelyi olobo ifa pelu pepeye
kan kio sib o ori re pelu agbon
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Agbon meji
Epo
Eko
Obi
Agbon meji
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Awo nijounki
Awo nijonhun kii
Awo nijonhun kinkin
Adifafun adaba susu igbati momi
Oju sogbere omo
Awo nijonhun kii
Awo nijonhun kinkin
Adifafun adaba susu igbati momi
Oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire omo fun eklelyi
pe oju omo ni opon elleyi kio bobo
ibeji pe yio di olomon kio si fi akuko adire meji rubo kio si fi opolopo ewa bo ibeji
pe oju omo ni opon elleyi kio bobo
ibeji pe yio di olomon kio si fi akuko adire meji rubo kio si fi opolopo ewa bo ibeji
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
akuko adire meji
opolopo ewa
epo
eko
obi
opolopo ewa
epo
eko
obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ewure abori gbongbo
Adifafun orunmila
Baba o laya meji loojo
Adifafun orunmila
Baba o laya meji loojo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire aya fun elelyi
pekorubo pe aya bo fun pe papajulo aya meji ni yio nip o lekan naa ebo ni kose kio sifi oruko rubo fesu
pekorubo pe aya bo fun pe papajulo aya meji ni yio nip o lekan naa ebo ni kose kio sifi oruko rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran oruko kan
epo
eko
obi
oti
epo
eko
obi
oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Otun isokun eru
Osin iso kun eru
Gbogbo e gbogbo e eru
Adifafun adaba susu
Igba ti n be nirogun ota
Osin iso kun eru
Gbogbo e gbogbo e eru
Adifafun adaba susu
Igba ti n be nirogun ota
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi
pe kio si rubo ope ogun tiowa
wi iwajure awon kan rope ogun naa koni semi EBOn hi kose ki ogun naa
ole bASE kio si lofi eran ewure bo ifa
pe kio si rubo ope ogun tiowa
wi iwajure awon kan rope ogun naa koni semi EBOn hi kose ki ogun naa
ole bASE kio si lofi eran ewure bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran ewure kan
epo
eko
obi
epo
eko
obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ao toju ewe ela ao toju
ewe aje ewe ire ao wa lo
meteta pelu iyere ao wa fi
se eyele funfun kan lepo ni
yo ao wa teiyere osun ni
odun ifa yin ao wa se adura
tabafe si ao wad a si obe
yin ao wa je
ewe aje ewe ire ao wa lo
meteta pelu iyere ao wa fi
se eyele funfun kan lepo ni
yo ao wa teiyere osun ni
odun ifa yin ao wa se adura
tabafe si ao wad a si obe
yin ao wa je
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao tioju ounkepe inu ewure ati ewe alupayida ao wa jopo mon odidi atare kana o wa fi si gbere si ori kerike ara ni meta meta ao wa di iyokun sinu epo pupa ao wa mon lasnu lale
Explore Ifa
Oturupon Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Irosun Odu.
