Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òkánràn Óbárà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the balance between wisdom and action.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-obara
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okiti baba nipeku opopo Adifafun oloba abedi Omo ariyinkunni bomo lenu Igba timomi oju sogbere Ire gbogbo Ebo ni won ni kose Osigbebo ni be orubo Nje egungun ile oloba Egbodojaye oru Orisale oloba Egbodajaye orun Eniyan ile olobe Egboda je fa orun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e ire gbogbo fun elelyi pe ki elelyi omu oju to awon irunmonle daradara kio si lobo ifa ati orisa pelu eku eja abodie igbin pupo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodie Igbin pupo Epo eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Okinti baba ni peku opopo Adifafun aso tigbogin ropin atari Ebo ni won ni kose Ogbe boni be orubo Nje eran ri tani win Gbogbo wa lajo lajolesun ni Ipako emon ri temiwi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oppe ire isegun fun eleyi ki elelyi orubo isegun kolo bo esu ori re pelu eran oruko kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Epo Eko Obi Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa Adifafun bata nijo tilolegba Roro obinrin sango Ebo ni won ni kose O gbebo ni be orubo Nje tomo tomo lanbo ebomi a mon lakanaa pipo sango gbaroro gbe roro

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe oun pere gbogbo fun elelyi pe oun sip e ire aya fun elelyi pe ki elelyi olo bo sango pelu agbo ati a mon la gbegirin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo kan Orogbo Amonla Epo eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa Adiafun ori ori tode orun bowale aye EBO ni won ni ki ori ose Ori si gbebo nibe o rubo Nje oju tomi oun oni borise Yio pada wa to ori wa Kere kere ori mon deleni Gbogbo ara ti won ni Awon oni ba ori se Won yio pada fori wa Kere kere ori mon deleni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire gbogbo fun elelyi ki Eleyi olobo orire daradara Pelu eye etu kio si fi eyele rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Eyele kan Epo Eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe gboro ao toju ewe omini ewe aje ewe sajeje ao wa lagbogbo re po ao wa fi se abo adire toti pamon ri kaje lepo niyo ao wa se adure si ao wa je obe naa ni ori ifa ni ao ti je oba naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju awo bata tabi ida oju bata ao wa gun mon ose dudud eni naa yio ma fi we un ojo mesan

Videos

Watch Òkánràn Óbárà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òkánràn Óbárà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Òkánràn Ogbè, Òkánràn Òyèkù, Òkánràn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òkánràn Óbárà Odu.