Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Okanran Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Okanran Meji symbolizes a balance between action and reflection. It suggests evaluating past actions while moving forward.
Listen
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran Kan ni hin Okaran kan lohun Adifa fun omu ijo ti lo le je olori larin ara Ebo ni won ni kose O gbebo nibe orubo Nje a momu je olori Gbogbo omo eni E monmon wa ewa sin. Ao mu ewe saworo pepe peluiyere ao fi se eyin adire merin lepo ni yo eni maa yio se adura si yio je ISEGUN

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire iyin fun eleyin pe ipo kan ni won fefi lo eleyin kio mun sope ohun ose kio le badi eni iyin kio si fun eyele kan borire.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Akinfoju oloju sowo kajere Adifa fun orunmila Baba yio fi irinwo sowo Yoo jere egberin oke Ebo ni won ni kose Ogbe bo ni be orubo Nje aje ni eni oni legberin Gbogbo e gbogboe legberun Ire gbogbo nieni oni legberin Gbogbo e gbogbo e legberin.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni pe ohun pe ire gbogbo fun eleyin ebo ni ko se papajulo kio mon moju to ikan ara re ju teni eleni lo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Epo Eko Obi Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Obale bopon gba ariri Ojo mon gba no rologango Adifa fun oni ti le omon afeyin ju segun Igba ti be ni rogun ota Ebo ni won ni ko se Ogbebo ni be orubo Nje ategungun atorisa Ko sorisa to le ba sango kogun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire isegun fun eleyin pe awon kan ni won gbe ogun ti eleyin ebo ni ko se kio si lo bo sango pelu akuko adire kan.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan Epo Eko Obi Orogbo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Bi elebo ope ni Ase fin koye ni Oro ti ko kan ni konuko lasoju Adifa fun eji okanran Ni jo ti sawo rele oun tile Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje eji okanran Igba tode tile lodoba Igba tode tile lo fe lewawon Igba tode ti le todoba.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire gbogbo fun eleyin pe ibi kan ni eleyin loyin korubo kole ba la ni ohun kio si lo bo ifa pe lu eku eja abodie ki aye ole ba gba ni ohun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodie Akuko die Epo Eko Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju epo obo ao gun mon ose dudu ao wa to ju aso fun fun aso pupa aso ayinrin ao wa mun meteta ao wa fi se kanhu kaihi naa yio fi we yio wa loso awon meteta yin sinu igbo rere.

Videos

Watch Okanran Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Òkánràn Ogbè, Òkánràn Òyèkù, Òkánràn Iwòrì, Òkánràn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Meji Odu.