Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Ni mu oloja agunte
Oun nije oba komo atoje
Adifafun eji
Igba tinbe lari ota
ao toju ewe ookun ao
toju ewe saworo pepe ao
wagon mon ose dudu
ao wa fi oju po ose
naa akoni ja ki omi
okan odi ojo keta kia
tobe re sini we ose naa
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
epo
eko
obi
Ese — Yoruba Verse
Okanfa
Adifafun Okun
Ti n sunku pe oun o ni aje lowo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
rubo kole balaje lowo
kio lobo orire pelu pepeye kio
fi akuko adie kan rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Erun nijoba ki omo otoje
Adifafun yeye fulani
Eyin tio tata tiyio tafa e
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
eleyi EBO ni kose kio si mon
pe ifa osi kio lofin ewure bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Awo ibon
Lose fafun iban
Nigba ti n be laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
EBO ni ki elelyi ose
Kio si lobo ogun pe lu aja kan kio si fi akuko adire bo esun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Okanran Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Okanran Iworin. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Okanran Iwori Odu.
