Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òkánràn Iwòrì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Okanran Iworin
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Okanran Iworin

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran hinhin Ni mu oloja agunte Oun nije oba komo atoje Adifafun eji Igba tinbe lari ota Ebo ni won ni kose Osigboebo ni be oprubo Nje ero po Ero ofa Ewabani laru segun ao toju ewe ookun ao toju ewe saworo pepe ao wagon mon ose dudu ao wa fi oju po ose naa akoni ja ki omi okan odi ojo keta kia tobe re sini we ose naa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere isegun fun elelyi ebo ni kose kosi lobo sango pelu oruko

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan epo eko obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Okanfin Okanfa Adifafun Okun Ti n sunku pe oun o ni aje lowo Ebo ni won ni kose O si gbebo ni be oprubo Nje okukan gboro Mo sope o laje mon Arape loku Arare laje gbenso

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere aje fun elleyi pe ko rubo kole balaje lowo kio lobo orire pelu pepeye kio fi akuko adie kan rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Pepeye kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran hinhin ni mu oloja gunte Erun nijoba ki omo otoje Adifafun yeye fulani Eyin tio tata tiyio tafa e Ebo ni won n i kose Osi gbebo ni be orubo Nje eropo Ero ofa E wa bani laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere isegun fun eleyi EBO ni kose kio si mon pe ifa osi kio lofin ewure bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran hinhin Awo ibon Lose fafun iban Nigba ti n be laarin ota Ebo ni won ni kose Osigbebo ni be orubo Ibon a ni oun Sebo okanran hinhin Oun segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire isegun fun eleyi EBO ni ki elelyi ose Kio si lobo ogun pe lu aja kan kio si fi akuko adire bo esun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran alakan Akuko adire kan Epo Eko Obi

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ekin iba ti won tiku sibe ao wa lo eyin toba selo ni b e ao wa fin si gbere mokan lalogun 21 si ari ori eni ao fi iyo ku foko mu

Videos

Watch Òkánràn Iwòrì teachings on our channel.

Explore Ifa

Òkánràn Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Okanran Iworin. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Òkánràn Ogbè, Òkánràn Òyèkù, Òkánràn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òkánràn Iwòrì Odu.