Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òkánràn Òwónrìn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Onile lo lare Ajoji omo se le omo Omile aon ate jeje Adifafun aye nijo tilole rale leru Ebo ni won ni kose Ogbebo ni be orubo Nje igba ti aye ti lale Ni ara tini aye kokoko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nip e ire gbogbo fun eleyi ki eleyi orubo kio si mon ta oun kan inin re tio ba si fe tahun ko bere won kio mon ba seta orire re mon oun ti o ba ta kio fi akuko adire meta rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meta Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kapebirin koto kamule Kapebinrin koto kamule Kamule kamon darawa Adifafun olokanran Nijo ti lole dari eku anaa Ebo ni won ni kose Ogbebo nibe orubo Nje olokanran won Olokan ra won ri ni Ero po Ero ofa E wa bani tisegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire isegun fun elelyi ki elelyi osi maa so otoo dara dara kio si lobo ile pelu eku eja orogbo obi atare pepeye ekuru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Pepeye kan Orogbo meta Obi meta Atare meta Ekuru funfun
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran owonrin onile lolare Ajoji omo sere Ajoji obamesere Omo onile atejeje Adifafun orun mila babasawo lo Sotufe rere Ebo ni won ni kose O si gbebo ni be orubo Nje tani be ni fe Toni tedun kosi ni be Tani be ni fe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa so pe ire okere fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyi ebo ni ki eleyi ose kio si lobo iofa pelu ewure kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe isin pelu ewe iya ao wa lopo ao wa fi se edo monlu je lepo ni yo ao wa se adura si dara dara ao wa je obe naa ao wa lori ikoko taba fi se be na man le akogbodo lomon ki obe naa ole si se daradara

Videos

Watch Òkánràn Òwónrìn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òkánràn Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Òkánràn Ogbè, Òkánràn Òyèkù, Òkánràn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òkánràn Òwónrìn Odu.