Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Okanran Irete

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu highlights the need for patience and perseverance.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/okanran-irete
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran reterete
Awo omi lose fafun omi
Nijo ti n be lagbatemon omo araye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki elleyi orubo isegun ota pe ota kan ni gbogun ti elelyi ebo ni kose kio si lobo ogun pelu akujko adire kan kio si lofi akujko adire kan rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji
Epo
Eko
Oti
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oni mo dafadafa ifami iboni
Ola mo dafadaf ifami iboni
Adifafun owere lanuja ti se
Omo bibi inu agbonmeregunn
Igba ti won ni korubo ni laiku
Arare
Ogbebo ni be orubo
Nje owere ni moja
Ni koje kiraye bakulo
Moti loba fa je yindiayindin
Ni koto akitan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire laiku fun elelyi ki elelyi olo bo ifa ni koto akintan pe lu eran elede kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi eran elede kan
Epo
Eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran reterate
Awo ori
Losefafun ori
Nijo ti n sunkun pe oun oleni kan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa so pe oun pe ire ifa fun elelyi pe oju ire gbogbo nip on eleyin ebo ni kose kio si lobo orire pe ni eja aro minla kan kio si fi eku eja abodie bo ifa naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan
Eja kan
Abodire kan
Eja aro ni nle kan
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

simi titi lawo simititi simijinaa lawo simijinaa tiba sio titi mi opade leyin re adifafun olokanran ti saw lo sotun ifa rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire gogbo fun elelyi lokere Ki o rubo kole bako ore okere dele ebo ni kose ki elelyi osi kote Ifa kia ara ola bade kio bo Ifa pelu eraan ewura kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe akisan pelu ata ijosin ao wa lopapo ao wa fi se eran elelde ekin ri merindinlogun lepo ni yo ao wa lomu aso funfun taba ti se oba yin tan ao wa aso funfun yin ao wa
se adura si obe obe yin ao wa je obe naa aso funfun yin ni ao wa di ilesu ojonaa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju irewe oju omi ao wa
lo ao wa po mon ose dudu
ao wa lowe si odo tobanusan fun
ojo meta

Videos

Watch Okanran Irete teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Irete Odu.