Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òkánràn Ìrètè

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for patience and perseverance.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran reterete Awo omi lose fafun omi Nijo ti n be lagbatemon omo araye Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje ekurire laba omi Iwa omi obuku Akibomi sofe Aki ba omi sola Eku rere labo mi iwa omi Obuku

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki elleyi orubo isegun ota pe ota kan ni gbogun ti elelyi ebo ni kose kio si lobo ogun pelu akujko adire kan kio si lofi akujko adire kan rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Epo Eko Oti Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oni mo dafadafa ifami iboni Ola mo dafadaf ifami iboni Adifafun owere lanuja ti se Omo bibi inu agbonmeregunn Igba ti won ni korubo ni laiku Arare Ogbebo ni be orubo Nje owere ni moja Ni koje kiraye bakulo Moti loba fa je yindiayindin Ni koto akitan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire laiku fun elelyi ki elelyi olo bo ifa ni koto akintan pe lu eran elede kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi eran elede kan Epo Eko Obi Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran reterate Awo ori Losefafun ori Nijo ti n sunkun pe oun oleni kan Ebo ni won ko se Osi gbebo ni be orubo Nje oju toloun oni ba ori se Kerekere won yio pada toriwa Gbogbo ara ti won ni awon oni Bi ori se krere kere Won yio pada to ori wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa so pe oun pe ire ifa fun elelyi pe oju ire gbogbo nip on eleyin ebo ni kose kio si lobo orire pe ni eja aro minla kan kio si fi eku eja abodie bo ifa naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodire kan Eja aro ni nle kan Epo Eko Obi Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

simi titi lawo simititi simijinaa lawo simijinaa tiba sio titi mi opade leyin re adifafun olokanran ti saw lo sotun ifa rere EBO ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje oundun emi owale mon Egbesin efoluwo olokanran Sare we a kowa te

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire gogbo fun elelyi lokere Ki o rubo kole bako ore okere dele ebo ni kose ki elelyi osi kote Ifa kia ara ola bade kio bo Ifa pelu eraan ewura kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao toju ewe akisan pelu ata ijosin ao wa lopapo ao wa fi se eran elelde ekin ri merindinlogun lepo ni yo ao wa lomu aso funfun taba ti se oba yin tan ao wa aso funfun yin ao wa se adura si obe obe yin ao wa je obe naa aso funfun yin ni ao wa di ilesu ojonaa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju irewe oju omi ao wa lo ao wa po mon ose dudu ao wa lowe si odo tobanusan fun ojo meta

Videos

Watch Òkánràn Ìrètè teachings on our channel.

Explore Ifa

Òkánràn Ìrètè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Òkánràn Ogbè, Òkánràn Òyèkù, Òkánràn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òkánràn Ìrètè Odu.