Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Okanran Obara

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu represents the balance between wisdom and action.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/okanran-obara
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okiti baba nipeku opopo
Adifafun oloba abedi
Omo ariyinkunni bomo lenu
Igba timomi oju sogbere
Ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e ire gbogbo fun elelyi pe ki elelyi omu oju to awon irunmonle daradara kio si lobo ifa ati orisa pelu eku eja abodie igbin pupo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku
Eja
Abodie
Igbin pupo
Epo eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Okinti baba ni peku opopo
Adifafun aso tigbogin ropin atari

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oppe ire isegun fun eleyi
ki elelyi orubo isegun kolo
bo esu ori re pelu eran oruko kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa
Adifafun bata nijo tilolegba
Roro obinrin sango

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe oun pere gbogbo fun
elelyi pe oun sip e ire aya fun
elelyi pe ki elelyi olo bo sango
pelu agbo ati a mon la gbegirin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran agbo kan
Orogbo
Amonla
Epo eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran bababa
Adiafun ori ori tode orun bowale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire gbogbo fun elelyi ki
Eleyi olobo orire daradara
Pelu eye etu kio si fi eyele rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan
Eyele kan
Epo
Eko
obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe gboro ao toju ewe omini ewe aje ewe sajeje ao wa lagbogbo re po ao wa fi se abo adire toti pamon ri kaje lepo niyo ao wa se adure si ao wa je obe naa ni ori ifa ni ao ti je oba naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju awo bata tabi ida
oju bata ao wa gun mon
ose dudud eni naa yio
ma fi we un ojo mesan

Videos

Watch Okanran Obara teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Obara Odu.