Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Òwónrìn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of adaptability and flexibility.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrinrosun koko loro Akabanla nin won fi gaka Awole ni n gbawo funwon loko Adifafun Orunmila Nijo toun ati sango jo n sota Ebo ni won ni ko se Orunmila nikna ni n be leyin ti n tubo Ero ipo Ero ofa E wa bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o bo oosun nitori awon merin kan ree ti won n ba eleyii sota, pe ko rubo ko le baa segun won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Epo Obi Eko Agbado Akuko adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Owanrin rosun koko loro Akasonla ni n won fi gaka Adifafun olofin aka Igba ti be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe awon ota nbe fun eleyii, pe ko fi oruko rubo ko le baa ni segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Epo igo meji Eko marun Agbado Opolopo owo

Videos

Watch Íròsùn Òwónrìn teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Òwónrìn Odu.