Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Íká

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-ika
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Atete nire Kosi eniyan to mosin orisa Ta ba jiyan jiyan Boriba yi ni le titi Bo ba pe titi orire nje Adifafun ogodo Tii se omo onipapo Igba ti n momi oju sogbere ire Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe orubo Nje, bori bayinyin nile titi bi a san no gbwyin wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa pe ki o rubo kire o le baa to lowo, ko sib o ori re ko mo ro ara re pin Ifa pere fun eni to dafa yii, ko rubo ki ire o le baa to lowo, ifa si tun pere oye fun Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa si pe ara ko ro, k obo baba re pelu alakan, ko si ba baba re ladehun pe koto di odun ti n bo, oun o wa fi ahun ati agbo loo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Opolopo owo Eyele Opolopo owo Eyele Agbebo adie Akuko adie Igbin opolopo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

MEDICINA Un camaleón seco se molerá en polvo y se usará para cocinar con carne de oveja con aceite de palma y sal, después de la cocción, uno lo pondrá sobre una parte de una olla de arcilla rota apaadi las nalgas no deberan de tocar el piso, y uno estara desnudo cuando sea la 1:00 am, en media noche, uno dira el rezo y lo comera todo NOTA: Esto se come en un plato de arcilla y se come en cunclillas MEDICINA 2 Itanna ewe esisi, itanna ewe taba, La raíz de la plantación de bananos se quemará junto con un pimiento de cocodrilo completo y se utilizará para hacer nueve incisiones en medio de la cabeza de uno

Videos

Watch Íròsùn Íká teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Íká Odu.