Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Òtùrùpòn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of introspection and self-discovery.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-oturupon
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Pansa ojugun han Obara dudu palapala Adifafun Orunmila Won ni baba o rubo Koju re o le baa kan bi pansa Ojugun naa obara dudu palapala Adifafun Omo eniyan Won ni won o rubo koju won o le ba kan Orunmila nikan ni n be leyin ti n rubo Orunmila lo bijokun IROSUN OUN IRETE ESE IFA Igbaa nla abi oro tooto legan Adifa fun won ni mesin ejeru Nibi ti won tin peru legbon nitori omo Won ni won orubo Ki won le baa bimo Won gbebo nibe won rubo Ero ipo Ero ofa E wa bani laarin omo Aarin omo lawa wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oju ire gbogbo n pon eleyii, pe ko rubo, ifa ni oun ti eleyii dafa si da, ko rubo ko le ba dero, ko lo bo esu ni akuko adie Ifa pe ki eleyii o rubo ija igbona, ko si rubo laiku arare pe yoo si rire Ifa pere fun eni to dafa yii, ko rubo, ifa ni eleyii lo ree pe ogun loun ba oun ja ati osa egun kankan, pe awon kan n be legbe re ti yoo fe maa ba nkan ini re je, pe ebo ni ko ru Ifa loun pere omo fun eleyi keleyi ko mo je iru nitori abiku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo Akuko Eyele Opolopo owo Akuko adie Opolopo owo Eku eja Abo adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Igi ajuba ni nii jongojongo Adifa fun ogun O ngbe ogun lo igbomekun eseji Awoni korubo alo ati abo Ogun fi gbigbo salaigbo O ko ebo beni korubu O fi eti otun gbebo ofi tosi danu Nje sure wa elenini ngbe milo Gbogbo orisa sure wa Elenini ngbe milo Oko kai ori baba elenini baba wa Keepe Kee jinna Ifa de alase ope asise wara wara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere isegun fun eleyi kosimo gbokanle agbara keleyi ko lo re boo gun pelu sango ko rubo nitori elenini

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akukodie Opolopoowo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Keke ni di won oku Apata ni di won oja Nijo eni baku Omo eni lorisa fidin won lede ni Adifa fun awo tunde Tii se elemoso awo lode orunwa Eyi toko isin ope To loun ose tifa mo Ebo ni won ni ose O si gbebo nibe orubo Nje awo tunde elemoso awo Eese to logbo tifa mo Orisa to ba gbe ni laa sin ESE IFA Olobiri koto lawo aweje wemun Adifafun olofin nife oun daye Won ni korubo komo se ojojo Ko mo towo eeri benu Ebo ni won ni o se O gbebo nibe orubo Nje orunmila moja sojojo Ifa moja towo eeri bonu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifa yi ko rubo ifa ni oju pon eleyi owa ni oun ko se tifa mo ko ma se be oifda ni ko gbebo fi oun sile komo sebi toun Ifa pere fun eni toda ifayi Ifa ni gbogbo oun toba tifeje ko mo fowo ko toje nitori arun ifa ni oun ko nije ki o se ojojo ko si ni towo eeri bonu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Akuko Opolopo owo Akuko Eyele Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Ota ridiridi awo ile kelekun Adifa fun kelekun Eyi to lohun ninu Ti n begun tin borisa Ebo ni won ni o se O si gbebo ni be orubo Nje kelekun loyun ninu O begun so Gboyun inu re idan ni ESE IFA Adogboloko adogboloko Adifafun orunmila Won ni baba onirikin re bo mo Ebo won ni o se O gbebo nibe o rubo Nje ifa seni mari obo ni gbayi o Oriri akasu akasu nan oriri Ewi ado ni se ni se Mario bo ni gbyin wa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda fayi korubo ifa ni obinrin kan ni yen to ni oyun komo bawon bu ogun ati orisa tori ki ojo ikunle re ko mo ba nira Ifa pere fun eni todafayi ifa ni awon kan wa bi pe ko le la mo laye korubko si fi eko bo fa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie Opolopo owo Eyele Akuko Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

(WEALTH) MEDICINA Dos Palomas, Dos ratas emón, hierbas emo, el emon agbo Rata se quemará todo junto y se verterán vino y uno lo tomará con Eko frío todas las mañanas (VICTORY) MEDICINA La raíz del palo atori se triturará y se usará para cocinar caracoles con aceite de palma y sal y después de la cocción la persona lo comerá cuando se enfríe. IROSUN ATERE ESE IFA Ajilowo awo won lode ilowo Ajiloro awo won lode iloro Moriwo olee ni sawo lode ilomo Adifafun orunmila Oju ti n pon ikin latesin Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe o rubo Won ni ki baba o fi isu eyele rubo Nje oju ti n pon ikin latesin nko Oungo isu ko sai ko ire gbogbo de poro poro Aje n wa mi bo wa o Apa otun, apa osi leyele fii ko re wole Tomi wa ara gbogbo ni sefun sefun fi n sefun aje Ire ti n wa mi bowa koni dabo atare ki di tire laabo Ifa ni oju aje lon pon eleyi korubo ki iponju re le dero Eyele merindilogun (16) Isu Opolopo owo Ewe esisi ao fi oti rega onike gbo dada ao lo igbo ti yo kunan loto ao lo egun ori gbi gbe loto ao wa damejeji si oun ti a gbo yi ai gbe mun ao se ki a tomun ojo kan nan ni ao fi mu kogbodo di ojo keji o

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ibepe ti kop on eyo kan o be epo arare kuro a o wa be kekeke sinu igo fun ge keke ke sinu igo funfun ao ro omi tutu si toba di ojo keta ni o toni gass kookan

Videos

Watch Íròsùn Òtùrùpòn teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Òtùrùpòn Odu.