Í
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Paa okun ni jamoju reefe
Adifa fun olosun
Ti won lorore onija diju
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe orubo
Aye lanje
Aye lawa nje
Oro awa ko mo jagidi mo
Aye lawanje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ire nbe fun eleyi sugbon awon aye o fe ma sele ni ni re
Ifa ni ki eleyi o mo feran obinrin kankan lo elelyi yo si bimo meta kan, ifa ni awon omo yii ni wongbija iya won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igba eyele
Eyele mejo
Opolopo owo
Gripia oruko
Tabi akakuko adire meta
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Irosun di lomode da
Omokekere kida idi aisun
Adifafun won nidin samu
Won ni won o fi aporobori
Won o le baa fo ju kan re
Ebo won ni won o se
Won si gbebo won rubo
Keepe
Kejinan
E wa ba mi je butu ire
ESE IFA
Sinmi titi lawo sinmi titi
Sinmejinan lawo sinmejinan
O le sin mejinan koba mi dele irosun towon nifa
Adifa fun oba alara yobe kinrin eye
Yo be kinrin eye
Yodemi kin kin si
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje koriko dide meruwa dide
E karele oba ka lolejo bata
Bi bata o re kalo jo abimon
Abimo pin pin pin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to dafayi korubo kole di olola kofi aparo bo ori tori ire ifa ni ire koni bo sonun lowo re
Ifa pere fun eni toda ifa yii, ifape ninu awon eleyi oun fi oju kere eni kan fo. Oun foju pe ko lese inkankan fun oun tabi ninu awon orere ifa ni komo foju di eyan ifape eni kan n be tin ja eleyi logun korubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aparo
Eyele
Opolopo Owo
Akuko adie
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Irosun di lomode da
Omo kekere kiida idi aisun
Adifafun orunmila
Baba momi oju sogbere aje
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jinan
E wa bani ni jebutu ire
ESE IFA
Igba nla abeekan niha
Adifa fun orunmila
Baba n sawo rele irosun towan nifa
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Keepe
Kee jinan
E wa bani nije butu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi, ifa ni oju aje nipon eleyi korubo kio le ba ni aje
Ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni ibi kan laleyi ninlo ko rubo kole kore bo nibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
Eyele
Abo adie
Akuko adie
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe sapo ewe ogede agbagba ewe saworopepe ewe ina epo konu koho tio babo sile funrare, ao gunpo mose ao fi lofinda bi tupo ao ko sinu ike funfun ao ma fiwe
Omundun ewe pandoro ao lomopomo iyere ao fi se odidi igbin kan leponiyo ti oba jinnan ao su aso funfun ni o suka ao so kanoru ao se adun sini ihoho
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo akerejupon mokanla ao jo odidi atare mokanla ao jo pomo arawon ao fi sin gbere meta meta si orikerike ara
Ewe sereyo egbo eti pon ola epo obo die odidi atare kana o jo po ao wa fi sin gbere yipo orun owo mejeji
Explore Ifa
Íròsùn Òdì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Òdì Odu.
