Í
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Jege jege teri akere ngbe
Iye niko se tu lokun
Adifafun orunmila
Eyi to ti taja sile
Ti gbogbo omo re o mo gbawo kiri
Ebo won ni kose
O gbebo nibe orubo
Ero ipo
Ero ofa
Ojo ti fa dale ni gbogbo wa ri na kirin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyi orubo ki ise re moba di ise onise korubo ki eni eni mo ba fi se faje ko lo ree bo ifa ki awon omo re ki won o mo ba se damu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Abodie ewure
Obi
Opolopon eyele
Opolpolo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Irosun funfun jingin
Adifafun olowo o jeran finfin alakedu
Igba ti n sogbogbo arun
Tin n nara kaka alailedide
Ebo won ni kose
O gbebo nibe o rubo
Nje kin ni polowo
Ai meewo ni polowo lo
Aimeewo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nipe alaisan wa larin eewo kan nbe nidile won kije eleyi nje ewo, ewo yi ewo na loda sile ko mo je ewo yi mo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Akukodie
Opolopo owo
Gbogbo nkan inu eran yi pese fun awon to laye
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Igi nla sidi omunre
Ato ro kin torokin
Adifafun orunmila
Baba loun o so a fin olufe di dudu
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Kee pe
Kee jina
E wa ba mi ni ni je butu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi korubo if ape awon mefa kan ni won o la eleyi ifa ni ise ti won ngbe bow a fun o le gan sugbon to ba rubo yo se ase yori kosi mun eun lele
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Oju iponkupon ni mun won wuwa kiwa
Adifafun orunmila
Baba n sawo lo ilu awon afin
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jinan
E wa bami ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni tofayi ifa ni keleyi orubo kele baji fa if ape oore olore yodi ti eleyi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Opolopo agbigba kan odidi atare kan ao fi eyin opolo yi le agbada ao fi odidi atare kan le laya ao wa ko ewe iya lode oyo
pomo arawon ao ni siwo titi yo fijo tan tio ba tan ao lo ao ma fi oti lo ni ekan naa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe areyin kosun ewe aje obale aojo po mo odidi atare kan o ma fi fo eko tutu mun laro.
Explore Ifa
Íròsùn Òfún is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Òfún Odu.
