Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Òfún

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Jege jege teri akere ngbe Iye niko se tu lokun Adifafun orunmila Eyi to ti taja sile Ti gbogbo omo re o mo gbawo kiri Ebo won ni kose O gbebo nibe orubo Ero ipo Ero ofa Ojo ti fa dale ni gbogbo wa ri na kirin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyi orubo ki ise re moba di ise onise korubo ki eni eni mo ba fi se faje ko lo ree bo ifa ki awon omo re ki won o mo ba se damu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodie ewure Obi Opolopon eyele Opolpolo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Irosun funfun jingin Adifafun olowo o jeran finfin alakedu Igba ti n sogbogbo arun Tin n nara kaka alailedide Ebo won ni kose O gbebo nibe o rubo Nje kin ni polowo Ai meewo ni polowo lo Aimeewo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nipe alaisan wa larin eewo kan nbe nidile won kije eleyi nje ewo, ewo yi ewo na loda sile ko mo je ewo yi mo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko Akukodie Opolopo owo Gbogbo nkan inu eran yi pese fun awon to laye
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Igi nla sidi omunre Ato ro kin torokin Adifafun orunmila Baba loun o so a fin olufe di dudu Ebo won ni o se O si gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jina E wa ba mi ni ni je butu ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to da ifayi korubo if ape awon mefa kan ni won o la eleyi ifa ni ise ti won ngbe bow a fun o le gan sugbon to ba rubo yo se ase yori kosi mun eun lele

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Oju iponkupon ni mun won wuwa kiwa Adifafun orunmila Baba n sawo lo ilu awon afin Ebo won ni o se O si gbebo nibe orubo Kee pe Kee jinan E wa bami ni jebutu ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni tofayi ifa ni keleyi orubo kele baji fa if ape oore olore yodi ti eleyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Opolopo agbigba kan odidi atare kan ao fi eyin opolo yi le agbada ao fi odidi atare kan le laya ao wa ko ewe iya lode oyo pomo arawon ao ni siwo titi yo fijo tan tio ba tan ao lo ao ma fi oti lo ni ekan naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ewe areyin kosun ewe aje obale aojo po mo odidi atare kan o ma fi fo eko tutu mun laro.

Videos

Watch Íròsùn Òfún teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Òfún is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Òfún Odu.