Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Obara dudu palapala
Adifafun Orunmila
Won ni baba o rubo
Koju re o le baa kan bi pansa
Ojugun naa obara dudu palapala
Adifafun Omo eniyan
Won ni won o rubo koju won o le ba kan
Orunmila nikan ni n be leyin ti n rubo
Orunmila lo bijokun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyii o rubo ija igbona, ko si rubo laiku arare pe yoo si rire
Ifa pere fun eni to dafa yii, ko rubo, ifa ni eleyii lo ree pe ogun loun ba oun ja ati osa egun kankan, pe awon kan n be legbe re ti yoo fe maa ba nkan ini re je, pe ebo ni ko ru
Ifa loun pere omo fun eleyi keleyi ko mo je iru nitori abiku
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo owo
Akuko
Eyele
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo owo
Eku eja
Abo adie
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Ka te ni tutu
Adifafun Orunmila
Won ni baba o rubo
Ki inu ile re ko ma baa se gbona
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopoowo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun Onimoba iko
Igba ti n je nirangun ota
Keke ni di won oku
Apata ni di won oja
Nijo eni baku
Omo eni lorisa fidin won lede ni
Adifa fun awo tunde
Tii se elemoso awo lode orunwa
Eyi toko isin ope
To loun ose tifa mo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi Ifa ni gbogbo oun toba tifeje ko mo fowo ko toje nitori arun ifa ni oun ko nije ki o se ojojo ko si ni towo eeri bonu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Opolopo owo
Akuko
Eyele
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Ajiloro awo won lode iloro
Moriwo olee ni sawo lode ilomo
Adifafun orunmila
Oju ti n pon ikin latesin
Ope ori okiti abagolo sele
Adifa fun orunmila
Ifa n raye alainiku
Ota ridiridi awo ile kelekun
Adifa fun kelekun
Eyi to lohun ninu
Ti n begun tin borisa
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni todafayi ifa ni awon kan wa bi pe ko le la mo laye korubko si fi eko bo fa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo owo
Eyele
Akuko
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
MEDICINA
Dos Palomas, Dos ratas emon, hierbas emo, el emon agbo Rata se quemara todo junto y se verteran vino y uno lo tomara con Eko frio todas las mañanas
(VICTORY)
MEDICINA
La raiz del palo atori se triturara y se usara para cocinar caracoles con aceite de palma y sal y despues de la coccion la persona lo comera cuando se enfrie.
IROSUN ATERE
ESE IFA
Ajilowo awo won lode ilowo
Ajiloro awo won lode iloro
Moriwo olee ni sawo lode ilomo
Adifafun orunmila
Oju ti n pon ikin latesin
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Won ni ki baba o fi isu eyele rubo
Nje oju ti n pon ikin latesin nko
Oungo isu ko sai ko ire gbogbo de poro poro Aje n wa mi bo wa o
Apa otun, apa osi leyele fii ko re wole
Tomi wa ara gbogbo ni sefun sefun fi n sefun aje Ire ti n wa mi bowa koni dabo atare ki di tire laabo
Ifa ni oju aje lon pon eleyi korubo ki iponju re le dero
Eyele merindilogun (16)
Isu
Opolopo owo
Ewe esisi ao fi oti rega onike gbo dada ao lo igbo ti yo kunan loto ao lo egun ori gbi gbe loto ao wa damejeji si oun ti a gbo yi ai gbe mun ao se ki a tomun ojo kan nan ni ao fi mu kogbodo di ojo keji o
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Irosun Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Oturupon Odu.
