Í
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Atete nire
Kosi eniyan to mosin orisa
Ta ba jiyan jiyan
Boriba yi ni le titi
Bo ba pe titi orire nje
Adifafun ogodo
Tii se omo onipapo
Igba ti n momi oju sogbere ire
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe orubo
Nje, bori bayinyin nile titi bi a san no gbwyin wa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa pe ki o rubo kire o le baa to lowo, ko sib o ori re ko mo ro ara re pin
Ifa pere fun eni to dafa yii, ko rubo ki ire o le baa to lowo, ifa si tun pere oye fun
Ifa pere fun eni to dafa yii, ifa si pe ara ko ro, k obo baba re pelu alakan, ko si ba baba re ladehun pe koto di odun ti n bo, oun o wa fi ahun ati agbo loo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
Eyele
Opolopo owo
Eyele
Agbebo adie
Akuko adie
Igbin opolopo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
MEDICINA
Un camaleón seco se molerá en polvo y se usará para cocinar con carne de oveja con aceite de palma y sal, después de la cocción, uno lo pondrá sobre una parte de una olla de arcilla rota apaadi las nalgas no deberan de tocar el piso, y uno estara desnudo cuando sea la 1:00 am, en media noche, uno dira el rezo y lo comera todo
NOTA: Esto se come en un plato de arcilla y se come en cunclillas
MEDICINA 2
Itanna ewe esisi, itanna ewe taba, La raíz de la plantación de bananos se quemará junto con un pimiento de cocodrilo completo y se utilizará para hacer nueve incisiones en medio de la cabeza de uno
Explore Ifa
Íròsùn Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Íká Odu.
