Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Irosun Owonrin

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of adaptability and flexibility.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/irosun-owonrin
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Owonrinrosun koko loro
Akabanla nin won fi gaka
Awole ni n gbawo funwon loko
Adifafun Orunmila
Nijo toun ati sango jo n sota
Ebo ni won ni ko se
Orunmila nikna ni n be leyin ti n tubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o bo oosun nitori awon merin kan ree ti won n ba eleyii sota, pe ko rubo ko le baa segun won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan
Epo
Obi
Eko
Agbado
Akuko adie
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Owanrin rosun koko loro
Akasonla ni n won fi gaka
Adifafun olofin aka
Igba ti be laarin ota
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo pe awon ota nbe fun eleyii, pe ko fi oruko rubo ko le baa ni segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan
Epo igo meji
Eko marun
Agbado
Opolopo owo

Videos

Watch Irosun Owonrin teachings on our channel.

Explore Ifa

Irosun Owonrin is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irosun Owonrin Odu.