Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Iwòrì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Iwori
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of introspection and self-awareness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-iwori
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Iwori

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Atepa Awori Babalawo Erin Lodifa ferin tin lo lee goke alo Ebo won ni Ose O gbebo nibe o rubo Nje itaku to ni kerin man wo do Toun erin lon lo IFA IRETEDI ISEGUN Kiwo Tedi Kemin Tedi Eni esin ba te man re lonje aji besin Adifa fun orunmila Awon ajogun orun o je o sun man ju Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Eba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo awon ota nda eleyi pada seyin, ibikan ree ti eleyi fee lo sugbon awon ota n di lowo won oje ki oroke tabi oore baba eleyi kan re awon ota ofe ki oto lowo Korubo kire eleyi o leto lowo Keleyi orubo amon ota koje ki eleyi osun, ki eleyii o rubo yio segun won, eleyii n la awon aala kan ti ko dara awon iko orun ni n won fe mu eleyi lo korubo kiwon o ma baa pa eleyii

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Ada kan Agbado Owo Epo Eko Agbado Akuko die kan Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Atepa Iwori Babalawo oba Lodifa fun oba Ti n be laarin ota Ebo won ni ko ba ose Oba si gbebo nibe orubo Ero ipo Ero ofa E wa bawo laru segun Kiwo Tedi Kemin Eni esin ba fe ma repa lon je aji be Adifa fun oosa nla oseremangbo Ti n be laarin ota Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Awon ota nda eleyi laa mun won ojeki pa re oka oun tin da wole ti eleyi bati pa se bee ni awon ota nyi mun si eleyi won oje ki ose oun tolese sugbon korubo a pare oman ka oun toba dawole Keleyi orubo yio segun ota, keleyi o si fi ewure kan rubo eegun eyin eran yi ai fi kun ebo ru eje ara eleyi ao fi kun eboru nitori awon iko ti eleyin ri kadara korubo kole baa segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Oruka Agbado Owo Epo Eko Agbado Alabahun kan Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Atepa Awori Babalawo oba Lodifa foba oba Igba ti n fomi oju sogbere aje Ebo won ni oba ose O gbebo nibe o rubo Kee pe kee jinan Aje wa jede tuturu Te nun man Tie teni laa te nu man Adifa fun dunundun Ti o tenun rete di Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Oloun irete din Undi irete di

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ni tori oju ajenpon eleyii, pe ajenbo feleyi ki osi rubo senu ise re, yio la gidigidi kosi maa so ooto Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi ti gbogbo aye osi man wipe ajede feleyi ki eleyi obun awon oni lu lowo ko si man lo si bi ti won ba tin se ariya daa da ni be ni re aje re yio ti to lowo ko si man wo aso daa da

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Eyele kan Owo Epo Eko Agbado Eyele meji Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Epo lose je su Akaso lodun gaka Obinrin se barin jokunrin lo Adifa fun oosala osere mangbo Tin sun kun poun otoju bare Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Nje morire nile Morire loko Ire to so nun ire de Kete Kete Abeeku poo poo Adifa fun orisa oko Nijo ti n sawo rebi atoke doke Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Aje wa je de tuturu.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyiorubo gbogbo oore eleyin lo ko yale re korubo kire olee yalere papa julo omore kan re ki won o maa borisa fun un, ori omo yii yoo man lanan fun baba re oore meji kan sin bo fun eleyi korubo leba do lomo Keleyi orubo daa da kaleyi ba se ru bo si bee ni re aje re yio se po to, ibikan si lele yin lo yi pe yio rire munbo keleyi osi man soro to dara lenu ni pa se bee ni re eleyi yio se telowo Ko si man bo aje daa da

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi igbin meji borisa pelu obi meji Epo Eko Agbado Abodie kan Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Isu ogiri sako eepo obo eeru alamo ao gun po man ose ao ti opolo aaye kan tele igba olomori ao ko ose lori ao man bu we ISEGUN Ao to ju ikoko kana so eleyi wo to fi dafa ao ko tele ikoko yi ao ko ewe peregun merindinlogun le lori eleyi yio fa omin fo orire si nu ikoko yi ao de pada ao lo bo man inun igbo

Videos

Watch Ìrètè Iwòrì teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Iwòrì Odu.