Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Òkánràn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Okanran
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the journey of perseverance and strength.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-okaran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Okanran

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Puu lolubu Purugudu loluya Adifa faribi leje Tii soko ariyaki Igba ti n be laarin ota Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni laru segun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo oun ati iyawo re, pe aarin ota ni won wa won o segun awon ota osi maa fi iyawo eleyi da laamun won o fe fi iyawo yii se agbana fun, ko bofa fun ifa ni oba segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Akuko die kan Owo Eku eja abodie ao fi bo fa
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Puu Lolubu Puru Gudu Loluya Adifa fun akin sowon Omo orun ojo Igba tin be laarin ota Ebo won ni ose Osi gbebo nibe o rubo Kee pe kee jinan E bani laru segun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ifa ni re isegun fun eleyi awon ota ti wa eleyi kiri, won fe fi oogun ba eleyi ja korubo, kosi sora fun inkan jije ni le ore ko ma je pe ibe ni won oti so eleyi mun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Puu lolubu purugudu lolua Adifa fun opera Ti n fomi oju sogbere aje suuru suuru Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinan Aje wa je de tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nire aje eleyin bo lato keere korubo ko le baa te lowo ire ola eleyi ti fe de odo re sugbon ko manun ko man man so gbogbo oun to bari sita

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Puu Lolubu Purugudu Loluya Adifa feegun Ti n sawo rebi atoke doke Ebo won ni o se O gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinan Aje wa je de turutu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni re aje feleyi ibi kan leleyin loyi, yio rire aje mun bo nibe yio si gbayi nibe, sugbon kobo eegun kotolo yio bo eegun ni eko oole akara eko obi oti.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Eepo obo imin orun ewe egele eeru alaman ao jo po epo la o man fi la laaro laaro

Videos

Watch Ìrètè Òkánràn teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Okanran. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Òkánràn Odu.