Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Irete Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Ofun
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of balance and harmony.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/irete-ofun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ofun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Tefun Tefun Kanrandaa
Adifafun fagbaa rin
Ti n be lawujo eleye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Aarin ota ni eleyi wa korubo, yio segun aarin ota na ni eleyi yio gbe titi yio fi segun awon ota o sini lefi eleyi se nkan kan, awonu ni won o maa wo eleyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Atefun yigi yigi yigi yigi
Adifafun ori
Ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ko si bo orire, ori eleyi ni yio ba eleyi segun pe aye n da eleyi laamu, gbogbo igba lawon ota n ba nkan eleyi je eleyi o wa rubo yio segun ori eleyi si duro tii olorun oba segun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Tefun tefun kanranundan
Adifa foba
Adifa fun akapo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire ola fun eleyi eleyi yio la lati pase oba tabi eeyan la sugbon keleyi o ma n lafojudio nitori ola eleyi yio po ti okiki re o si kan laarin ilu.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Tefun tefun kanrandan
Adifafun aniya lorun
Igba ti n fomi oju sogbere ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere aje lati okeere fun eleyi keleyi rubo ko si fi ekuru funfun bo aje ati ori ko si fi eku emo bori iyare ati aso funfun ko si ma n toju iyare dada nitori ori iyare ni yio laa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
Eku eman

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ewe alupaida eeku ijebu eeru alaman iha eeso alu gbanko ao jo gbogbo re po ao man fi fokomu

Videos

Watch Irete Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Ofun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Ofun Odu.