Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Osa
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability in navigating challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Osa

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Arote sa Arote sojo Arote pakube kube Adifa fun okete oun efon jo n sota Ebo won ni won ose Okete nikan ni n be leyin tin tubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ota kan ree tolagbara ju eleyi lo korubo yio segunre ko si bo egbe re, awon egbere ni o baa segun Ota re naa, kosi dimo ifa daa daa ko mon bo fa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Akuko die kan
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Arote sa Arote sojo Arote pakube kube Adifa fun enlojo opolo Won o jin sofin omo araye Ebo won ni won ose Won si rubo Nje olufonyo ni yo man ho ho ho.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo awon ota ti gbe koto le de eleyii, korubo ko man baa jin si ofin ota, ko si bo orisa nitori ogun kan ni bo fe leyi orisa ni yio ba segun to ba segun nan tan ko man gbagbe oosa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Arote sa Arote sojo Arote pa kube kube Adifa fun orunmila Baba n sawo rele olokun sannin ade Ebo won ni fa ose O gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinan E wa bani bola ba peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi, ibi kan leleyin lo yii, yio ri aje mun bon in be, eeyan nla ni eleyi nlo si odore, pe lati ipase eeyan nla na oun nan yio di eni ola.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Eyele kan
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Arote sa Arote sojo Arote pa kube kube Adifa fun oosa nla oseremogbo Nijo ti n fomi oju sogbere aje Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinan Aje wa jede tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe keleyi orubo ajenbo feleyi, keleyi o fi etu bo fa kire aje ole de fun ko sibo orisa nitori orisa lo un dako ire aje re wa fun oju aje tin pon eleyi lo do orisa ni re re wa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Etu

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori ikun kan ori sebe kan ori elulu kan odidi atare kana o jo po man fi fo ko mun

Videos

Watch Ìrètè Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Osa. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Ósà Odu.