Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Irete Irosun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Irosun
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu signifies the power of patience and strategic planning.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/irete-irosun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Irosun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ateniwun Irosun
Oba buu bu balawo ori
Adifa fun ori
Tin be laarin ota
IFA IRETE OWANRIN
Atewonrin Atewonrin
Adifa foosa oko agbarawo
Ti n sowo rebi atoke doke
Awon ota ni ko ni de

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ota nda laamu, ko fi obi bo rire, Ori re ni yio ba segun pe ayen da eleyi laamu, won o je ki eleyi ogberi, bi eleyi se n se wahala eleyi awon aye oje ki won oman eleyi sugbon asiko to ti eleyi osegun
Keleyi orubo ibikan leleyin lo yi awon ota sope ko ni de korubo yio de ti oju osi ti awon ota re keleyi osi bo orisa oko orisa oko ni yio gba eleyi le lowo awon ota.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Opolopo abere
Ori ejo
Owo
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ateniwun Irosun
Oba buu bu
Adifa fun oosa oko agbarawo
Igba tin be laarin ota
Atewonrin Atewonrin
Adifa folongbo jigolo
Ti n lo lee ba won naja taye o maa ra

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ko bo orisa oko orisa oko ni yio ba eleyi segun Ni tori awon ota n wo ibi ti eleyi oba ja Sugbon eleyi o se gun ota re Keleyi osi man so oro enun re daa da.
Keleyi orubo ire isegun ota feleyi lenu ise eleyi ogbodo lo si ibi ipade lenun loolo yii nitori awon ota ti mun ra le de eleyi ni pade keleyi osi ma maa binu lenu looloo yi kipa ota o man baa ka eleyi.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi obi meji bo orisa oko
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Tenkolobo ileyi ogbaaye
Adifa feegun
Ti n fomi oju sogbere ire gbogbo
Tipepere Lase
Adifa fun orunmila
Ifa obori ola ni poro oko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ire aje nbo feleyi, kele yii osi bo eegun eleyi yio deni ti aye o man pesin awon oku orun eleyi yio la awon eleyi ko fi akara bo oku orun re nitori awon ni won oda ko irere wa fun
Keleyi orubo ko si bori ore re kan yoo la lodun yi niu pooro oko ni eleyi yoo ti bori ore re nan, ori ore eleyi ni ola.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Ao fi obimeji bo eegun
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi agbon meji bori
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oba mi lojude baba min
Iwo otete ki mi
Iwo o tete mo peni re lo bi mi lo mo
Adifa fun orunmila
Baba o gbare mun sigi
Tipe Pere Lase
Adifa fun orunmila
Baba lo un ogbare mun sigi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ire aje nbo feleyi ko rubo kosi bo fa nitori eleyi o gbare mun bi eleyi se n ri owo ko man bi se n tan sugbon keleyi o bofa kire eleyi o oleba mo duro lowo re
Keleyi orubo ire aje koduro lowo re, ko rubo kire re ole ba duro lowo re keleyii o si bofa re pelu eku, eja abodie nitori orunmila ni oun yoo dako ire eleyi wa fun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi eku eja abodie obi meji bofa
Epo
Eko
Agbado
Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ao to ju ori ejo eyi ke yi oko atare kana o lo po ao fi sin gbere kan siwaju
ISEGUN
Awo ejo eepo obo ebo sile ko nun ko ho ao gun po mo se ao maa fi we

Videos

Watch Irete Irosun teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Irosun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Irosun Odu.