Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Oba buu bu balawo ori
Adifa fun ori
Tin be laarin ota
IFA IRETE OWANRIN
Atewonrin Atewonrin
Adifa foosa oko agbarawo
Ti n sowo rebi atoke doke
Awon ota ni ko ni de
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ibikan leleyin lo yi awon ota sope ko ni de korubo yio de ti oju osi ti awon ota re keleyi osi bo orisa oko orisa oko ni yio gba eleyi le lowo awon ota.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Opolopo abere
Ori ejo
Owo
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Oba buu bu
Adifa fun oosa oko agbarawo
Igba tin be laarin ota
Atewonrin Atewonrin
Adifa folongbo jigolo
Ti n lo lee ba won naja taye o maa ra
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ire isegun ota feleyi lenu ise eleyi ogbodo lo si ibi ipade lenun loolo yii nitori awon ota ti mun ra le de eleyi ni pade keleyi osi ma maa binu lenu looloo yi kipa ota o man baa ka eleyi.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ao fi obi meji bo orisa oko
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Adifa feegun
Ti n fomi oju sogbere ire gbogbo
Tipepere Lase
Adifa fun orunmila
Ifa obori ola ni poro oko
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ko si bori ore re kan yoo la lodun yi niu pooro oko ni eleyi yoo ti bori ore re nan, ori ore eleyi ni ola.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Ao fi obimeji bo eegun
Epo
Eko
Agbado
Owo
Ao fi agbon meji bori
Ese — Yoruba Verse
Iwo otete ki mi
Iwo o tete mo peni re lo bi mi lo mo
Adifa fun orunmila
Baba o gbare mun sigi
Tipe Pere Lase
Adifa fun orunmila
Baba lo un ogbare mun sigi
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ire aje koduro lowo re, ko rubo kire re ole ba duro lowo re keleyii o si bofa re pelu eku, eja abodie nitori orunmila ni oun yoo dako ire eleyi wa fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ao fi eku eja abodie obi meji bofa
Epo
Eko
Agbado
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao to ju ori ejo eyi ke yi oko atare kana o lo po ao fi sin gbere kan siwaju
ISEGUN
Awo ejo eepo obo ebo sile ko nun ko ho ao gun po mo se ao maa fi we
Explore Ifa
Irete Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Irosun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Irosun Odu.
