Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Irete Okaran

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Okanran
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu signifies the journey of perseverance and strength.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/irete-okaran
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Okanran

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Puu lolubu
Purugudu loluya
Adifa faribi leje
Tii soko ariyaki
Igba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo oun ati iyawo re, pe aarin ota ni won wa won o segun awon ota osi maa fi iyawo eleyi da laamun won o fe fi iyawo yii se agbana fun, ko bofa fun ifa ni oba segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo
Eku eja abodie ao fi bo fa
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Puu Lolubu Puru Gudu Loluya
Adifa fun akin sowon
Omo orun ojo
Igba tin be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ifa ni re isegun fun eleyi awon ota ti wa eleyi kiri, won fe fi oogun ba eleyi ja korubo, kosi sora fun inkan jije ni le ore ko ma je pe ibe ni won oti so eleyi mun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Puu lolubu purugudu lolua
Adifa fun opera
Ti n fomi oju sogbere aje suuru suuru

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nire aje eleyin bo lato keere korubo ko le baa te lowo ire ola eleyi ti fe de odo re sugbon ko manun ko man man so gbogbo oun to bari sita

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Puu Lolubu Purugudu Loluya
Adifa feegun
Ti n sawo rebi atoke doke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni re aje feleyi ibi kan leleyin loyi, yio rire aje mun bo nibe yio si gbayi nibe, sugbon kobo eegun kotolo yio bo eegun ni eko oole akara eko obi oti.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Eepo obo imin orun ewe egele eeru alaman ao jo po epo la o man fi la laaro laaro

Videos

Watch Irete Okaran teachings on our channel.

Explore Ifa

Irete Okaran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Okanran. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Irete Okaran Odu.