Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Babalawo Erin
Lodifa ferin tin lo lee goke alo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
kire eleyi o leto lowo
Keleyi orubo amon ota koje ki eleyi osun, ki eleyii o rubo yio segun won, eleyii n la awon aala kan ti ko dara awon iko orun ni n won fe mu eleyi lo korubo kiwon o ma baa pa eleyii
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Ada kan
Agbado
Owo
Epo
Eko
Agbado
Akuko die kan
Owo
Ese — Yoruba Verse
Babalawo oba
Lodifa fun oba
Ti n be laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo yio segun ota, keleyi o si fi ewure kan rubo eegun eyin eran yi ai fi kun ebo ru eje ara eleyi ao fi kun eboru nitori awon iko ti eleyin ri kadara korubo kole baa segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Oruka
Agbado
Owo
Epo
Eko
Agbado
Alabahun kan
Owo
Ese — Yoruba Verse
Babalawo oba
Lodifa foba oba
Igba ti n fomi oju sogbere aje
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo ire ajenbo fun eleyi ti gbogbo aye osi man wipe ajede feleyi ki eleyi obun awon oni lu lowo ko si man lo si bi ti won ba tin se ariya daa da ni be ni re aje re yio ti to lowo ko si man wo aso daa da
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Epo
Eko
Agbado
Eyele meji
Owo
Ese — Yoruba Verse
Akaso lodun gaka
Obinrin se barin jokunrin lo
Adifa fun oosala osere mangbo
Tin sun kun poun otoju bare
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Keleyi orubo daa da kaleyi ba se ru bo si bee ni re aje re yio se po to, ibikan si lele yin lo yi pe yio rire munbo keleyi osi man soro to dara lenu ni pa se bee ni re eleyi yio se telowo Ko si man bo aje daa da
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ao fi igbin meji borisa pelu obi meji
Epo
Eko
Agbado
Abodie kan
Owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Isu ogiri sako eepo obo eeru alamo ao gun po man ose ao ti opolo aaye kan tele igba olomori ao ko ose lori ao man bu we
ISEGUN
Ao to ju ikoko kana so eleyi wo to fi dafa ao ko tele ikoko yi ao ko ewe peregun merindinlogun le lori eleyi yio fa omin fo orire si nu ikoko yi ao de pada ao lo bo man inun igbo
Explore Ifa
Irete Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Irete Iwori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Irete Ogbe, Irete Oyeku, Irete Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irete Iwori Odu.
