I
This Odu represents the need for balance and harmony to achieve success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni eba lele
Adifafun pepeye
Ti o mon sowo eku ni riru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii o mon se nkan ti agbara re ko nika ntori ti oba se yoo di eni yepere lawujo ki osi gbo nkan ti ifa bawi fun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo igbin
Epo
Eko
Akuko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo
Iyi lori gbogbo nkan
Ti o ba dawole
Ki osi mon pe oun jo
Ara oun loju
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Akuko adie kan
Obi
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyii orubo
Iyi lawujo opolopo
Awon eeyan
Ki osi bo eegun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori oreku
Egungun ogbodo na babalawo
Babalawo na o gbodo na eegun
Njo eegun ba na babalawo
Babalawo ani towotese
Ni alabahun fi n wo gba
Owo won o pada mon koole ni aso omo faya mon eegun loju Nijo babalawo ba na egungun
Egungun a ni towotese lahun fi n wonu
Adifafun onigbeyin aruku
Igbati n fomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Agbeboadie meji
Eyele meji
Epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AJE (riqueza)
Eeso emi ao lo pelu iyere ao fi se eja akan kan lepo niyo je ao se adure si odu ifa iwori oreku ti afi iyere osun te ao je
Explore Ifa
Iwori Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Odi, Iwori Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Oyeku Odu.
