Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Otura Irete

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the need for patience and perseverance.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/otura-irete
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Petenbole Okirini Kisi Ka susu oo le kafi disa eera Adifafun ijimere To oun aaya jo n sota Ebo won ni won o se Ijimere ni nkan ni be leyin ti n tubo Ero ipo Ero ofa E ba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ko si bo eegun pe eegun ni o ba eleyi segun ota Ore eleyi kan si ree ti won jo n sore, ko sora fun ore naa nitori ore naa yio gbabode fun ko si ma maa so oro enu re fun eleyi tan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo A o fi eko olele, obi, ati oti bo eegun.
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Eti erin ni odojo poju erin Adifafun orunmila Baba n be laarin ota Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Eba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyii o rubo ko maa woran lenun loo lo yii nitori kire ajere ole to lowo, nitori ire aye eleyi ni orunmila wa lo toba wa nbo toba ba eleyi lode o ijo yio wo wipe eyin ewo eni toun torire nwa ajere kiri ki orunmila o maa baa wa ko irere fun elomi.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

A da taka agbigbo Adifafun igunnugun Omo agbelu jofe Igba ti n tomi oju sogbere ire gbogbo Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni bola ba pere gede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, eleyi n se wahala kotori Owo sugbon korubo ko ni se wahala mo koto ma n rowo sele aye omo orunmila ni eleyi ise awo leleyi yio se to yi o fi da

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Etu Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Pepele ni ogbeleji Adifafun orunmila Baba o fowo adugbo se tie Ebo won ni o se O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni ni moro ire.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo pe ire eleyi n be ni to si ire kire re ole te lomo keleyi osi ma n ma n se ahun ko si dimo oun ifa daada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ori ikun meji ori alegba meji ikoode meji odidi atare kan a o jopo oyin la o ma n fi laa laaro laaro

Videos

Watch Otura Irete teachings on our channel.

Explore Ifa

Otura Irete is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Oyeku, Otura Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Otura Irete Odu.