I
This Odu signifies the importance of vigilance and awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ese rere karode
Adifafun awusa
Ti nfomi oju sogbere omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire omo fun eni ti o da ifa iwori osa ki omo re o le po dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie merin
Eyele merin
Epo ati eko
Obi
Oti
3
Ese Keta
Ese Keta
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Iwori oje awusa
Ara otan oje aja
Adifafun awusa kole badi
Olomo laye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori omo ki awon omo ti o ba sibi ole gboro si ara won lenu ko rubo ki won o mon ba mon se ota si ara won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Pepeye meta
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori pepeye ti won fi rubo ao jo pelu oko atare kan yio mon fi epo pupa la lalelale
Eye etu to fi rubo yi yio la laya pelu eyele kan yio fi opolopo ewe awoyoyo kun yio jo papo yio mon fin oyin laa nigbakugba
Explore Ifa
Iwori Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Iwori Osa Odu.
