Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oturupon Irosun

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of patience and strategic planning in achieving success.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oturupon-irosun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Orobo topo Adifafun ogo Tii se omo kuurin soku Igba ti n momi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun elelyi ki elelyi olobo ifa pelu pepeye kan kio sib o ori re pelu agbon

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye kan Agbon meji Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Awo nijounki Awo nijonhun kii Awo nijonhun kinkin Adifafun adaba susu igbati momi Oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire omo fun eklelyi pe oju omo ni opon elleyi kio bobo ibeji pe yio di olomon kio si fi akuko adire meji rubo kio si fi opolopo ewa bo ibeji

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

akuko adire meji opolopo ewa epo eko obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ewure abori gbongbo Adifafun orunmila Baba o laya meji loojo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire aya fun elelyi pekorubo pe aya bo fun pe papajulo aya meji ni yio nip o lekan naa ebo ni kose kio sifi oruko rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan epo eko obi oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Otun isokun eru Osin iso kun eru Gbogbo e gbogbo e eru Adifafun adaba susu Igba ti n be nirogun ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi pe kio si rubo ope ogun tiowa wi iwajure awon kan rope ogun naa koni semi EBOn hi kose ki ogun naa ole bASE kio si lofi eran ewure bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran ewure kan epo eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe ela ao toju ewe aje ewe ire ao wa lo meteta pelu iyere ao wa fi se eyele funfun kan lepo ni yo ao wa teiyere osun ni odun ifa yin ao wa se adura tabafe si ao wad a si obe yin ao wa je

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao tioju ounkepe inu ewure ati ewe alupayida ao wa jopo mon odidi atare kana o wa fi si gbere si ori kerike ara ni meta meta ao wa di iyokun sinu epo pupa ao wa mon lasnu lale

Videos

Watch Oturupon Irosun teachings on our channel.

Explore Ifa

Oturupon Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oturupon Irosun Odu.