O
This Odu emphasizes the need for embracing change and new beginnings.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ogbologbo oda abiroromin
Adifafun gbako ti n be laarin ota
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, owo mi w ate ewe segun sete oko temi
Ifa wa bamin segun ota mi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o rubo, pe omo odo eleyii yoo gbabode fun un, ifa ni ki eleyii o rubo ko le ba a segun re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Obi meji
Oti
Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Elubo danun manu
Adifafun Oye gbalaja
Ti n be laarin ota
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, osan gangan laagbariwo ninle ikun
Ifa o to gege ki n maa gbariwo nile ota mi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo isegun ota, ifa n ota eleyii yoo ku laipe yii, ki eleyii o maa lo ku laipe yii, ifa ni ki o ma lo kiwon ninle ota naa o.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ikun
Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Imu kurudu
Epa kurudu
Adifafun won lokonjo
Ire aje won n silo
Ebo ni won ni won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Nje, ire aje to ti silo npada bowa
Were rerere esisan unsanbo rerere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Gbogbo ohun tenu nje
Epa, Ireke, aadun,
imunmun, ogede
Eyin, ekuru, oyin, Akara
Obi
Oti
Abo adie kan, epo eko agbado
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Igi nla sidi
Igi nla wu
Igi nta manra
Adifafun Aje ti n fomi oju sogbere oko
Igi nla sidi
Igi nla wu
Igi nta manra
Adifafun awe
Ti fomi oju sogbere aya
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Ero ipo
Ero ofa
E ba ni bola peregede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni awon meji ree ti won wa aje, ki won o jo rubo, kire aje naa o le baa towon lowo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji
Abodie meji
Epo pupa
Eko, Agbado
Opolopo owo.
VERSE FOUR
Explore Ifa
Otura Oyeku is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Otura Meji, Otura Ogbe, Otura Iwori, Otura Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Otura Oyeku Odu.
