Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
I

Iwori Ose

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/iwori-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori wowo wowo Ifa ni wiro wokun wokun Iwori wokun tan Koto wode Adifafun enlojo agan Ti ntorun bo wa saye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe awon ni ti won nwa omo ifa pe ebo ni ki eleyi o mo rukole ba di olomo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo igbin Agbeboadie merin Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Iwori wese wese Adifafun Aase mon gamonga Ti won ni ko rubo Ogun omo araye Igba aitubo Igba aiteru Eri ifa awo ki bi ti n se Ifa de alase ope abise warawara

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo laarin opolopo awon ti won jo nse nkan papo ti o mon je pe ti e ni o ni gbayi lawujo awujo awon joku

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Eyele meji Epo ati eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Iwori wowo wowo Iwori wokun wokun Adifafun won ni Isese Asere Ibi ti won ti moju owo ju omo lo Eyin pele ara isese asere Te mon oju owo ju omo lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon mon oju owo ju omo lo Ifa ni omo ni yio la eleyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji Eye etu meji Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Aba awo ile Oniseri Adifafun oniseri Ni kutukutu awuro Igbati nfomi oju sogbere Ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire ola fun eleyi sugbon ko mo deja nkan ti won basofun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji ebo Eyele meji ebo Akuko adie meji fun ebo Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AJE Ewe adosusu aolo pelu iyere ao fi se eja ajabo kan lepo niyo ao te ifa iwori wowo sinu opon pelu iyere osun ao se adura si ao je gbogbo re pata.

Videos

Watch Iwori Ose teachings on our channel.

Explore Ifa

Iwori Ose is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Iwori Meji, Iwori Ogbe, Iwori Oyeku, Iwori Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Iwori Ose Odu.