Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Òwónrìn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Òwónrìn Excerpt
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oye wonrinmin Oye sorinje Oye sorinje paka paka sorinje Adifafun onin waka waka Toun aje jo n sota Ebo ni won ni ki won o se Onin waka waka ninkan ni n be leyin ti n be tubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eni kan ree ti ko jen kankan ofe, maa deru ba eleyii, pe ki eleyii o maa jeki eni toni nkan naa o nindi eru re.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abe fele Akuko adire kan Epo pupa Eko Opolopo owo Agbado Aso eni yii toni awo winnin winnin
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oye wonrinmin Oye sorinje Oye sorinje paka paka sorinje Adifafun Ajibowu tii somo alagbede iwoye Igba ti n be laarin ota Ebo ni won ni ki o se Ajibowu nikan ni n be leyin ti n tubo Ero ipo Ero ofa E bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni kele o sora pe eni to sun mon eleyii kan lota re, ki o rubo pe yoo segun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abe fele Akuko adire Epo Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oye wonrinmin Oye sorinje Oye sorinje paka paka sorinje Adifafun baba Baba n sawo relu aje Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Aje wa jede tururu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyii n lo si ibi kan pe korubo pe yoo rire bo nibe.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Eyele kan Epo igo kan Eko meji Agbado Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Yangi abori kugu Adifafun oosa nla oseremagbo Nijo baba n sunkun pe oun rire Ebo ni won ni o se O si gbebo nibe o rubo Nje, mo rire ninle Morire loko Ire to sonun Ire wole de

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pan eleyii korubo, pe yoo ri oore ninle re ati ni irin ajo lokere.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo igbin Ekuru funfun Epo Eko Opolopo owo

Videos

Watch Òyèkù Òwónrìn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Òwónrìn Odu.