Ò
Òyèkù Íròsùn Excerpt
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Igi nla yoninju
Ojue tole kokoko
Adifafun eegun abufun euru
Igba ti won jo n sota
Ebo ni won ni ki won o se
Eegun nikan ni n be leyin ti n tubo
Ipin aisebo
Ipin euru
Eyin orori fere lori eegun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyii o soro pe ota nla kan ree fun eleyii, ota yii ju eleyii lo, pe korubo ko si ma jaya pe yoo segun eni naa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ekuru funfun
Eyele funfun meji
Abo adie
Eku meji
Eja meji
Epo pupa
Eko
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oyeku rusu rusu
Adifafun won legba eesu
Nibi won ti nkori aje jo
Ebo ni won ni ki won o se
Won si gbebo nibe won rubo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bani bola ba peregede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni keleyii o rubo pe won o fi eleyii se olori kan nibe pe ibe si ni eleyii yoo ti di olola laye re.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo oka baba
Akuko adire kan
Epo pupa
Eko
Agbado
Opolopo owo
Explore Ifa
Òyèkù Íròsùn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òyèkù Íròsùn Odu.
