Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Òsé

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the need for cleansing and renewal to overcome past difficulties.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Olowo nin foko Olofa aferu Iwooraala Emi o raala Aroko ma raala lodijale Adifafun foyeku Ti yoo pakin ose soko nitori ija ogede Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ban in larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o ma ja sile oko tabi keleyii o sora fun orere pelu ija

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Elede kan Ogede agbagba Obi Owo, Oti, epo Eko, agbado ati owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Olowo nin foko Olofa aferu Iwooraala Emi o raala Aroko ma raala lodijale Adifafun Bayarin ti n be loko iwofa Ebo ni won ni ko se O sigbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo senu ise re, pe awon ota po feleyii lenu ise re, pe ebo ko le ba a segun ni ko ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Epo Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ojonla nin sewe koko rororiri ririroro adifafun oosa nla oseremagbo Ti n sunkun pe oun o foju bare Ebo ni won ni ko se O sigbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo nitori pe ire aje n bo fun eleyii, ko sibo orisa nla oseremagbo kire aje naa o le baa je fun un.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin mejo Obi meji Oti Epo Eko Agbado Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ketekete abeeku poopoopo Adifafun Omosun an abera owo Eyi ti yoo firinwo sowo Ti yoo jeer egbeje oke Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo senu ise re, pe yoo ri ola naa lenu ise ti oun se.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Epo Eko Agbado Opolopo owo

Videos

Watch Òyèkù Òsé teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Òsé Odu.