Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Ògundà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Òyèkù Ògundà Excerpt
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-ogunda
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Atorinla abidi gbdagi adifafun fojonda tii somo aja niwarun Igba ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, ojo ti mo da eepe Keni ma wule saloore

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo nitori pe laarin ota ni o wa, ki o le baa segun gbogbo won.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Abo adie kan Eyele kan Epo pupa Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Elegede ni n sawo inu igbo Eremi ni n sawo awujaale Adifafun folunlawe ti n je laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, owo te ewe segun sete temi Ifa o to gege ki n maa segun ota mi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo toripe aarin ota ni eleyii wa, pe ki eleyii o si se saara fun oku orun re ko le baa ni isegun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewe segun sete ni isale igba ebo Akuko adire meji Epo pupa Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Bebe o kehin Bebe oke oun Adifafun Orisa nla oseremagbo Ti o n sunkun pe oun o foju bare Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Morire nile Mo rire lode Ire to sonu, ire wole de

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oore aje n bo lati okeere wa fun eleyii ati nibi ti eleyii ti n gbe pe o n saroye pe oun ko lowo lowo, pe ko rubo pe ire aje n bow a fun un.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin merin Eyele funfun meji Epo Eko Obi merin Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oriri mori awo oba Adifafun Oba Ti n fomi oju sogbere aje sururu Ebo ni won ni ko se O gbebo nibe o rubo Ko e pe o Ko e jinna Aje wa jede tururu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loju aje n pon eleyii pe ko rubo, ko si fi ogede ominin, eyin, ekuru funfun bo aje, aje yoo joko ti eleyii.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo eran ogede Eyele meji Opolopo oeo Agbado

Videos

Watch Òyèkù Ògundà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Ògundà Odu.