Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Oyeku Meji

Oyeku Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Oyeku Meji signifies profound transformation and renewal. It suggests a powerful change in ones life.
Listen
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/oyeku-meji
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyesese labo loke
Omo araye se bi oju mo lomon
Adifafun baba yeku yeku
Ti won o mope ni oyeku sapana

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii orubo laiku pe ki emi re ole gun ebo ni kose dada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan
Epo
Eko
Obi
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Opa gbogbo ni siwaju agbon nini
Ese mejeji ni jija de ona gborogan gborogan
Ati pe obi enu bobo aso kitipa abita wele
Adifa fun enlojo aso
Lojo ti won tode orun bo wale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki awon omo iya meta ki won o rub o emi won ki emi won ba le gn ti won ofi aso dudu aso funfun ati aso pupa kobo ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aso dudu
Aso pupa
Aso funfun
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Atefa bere arobiunda
Apaju bere airobiunko
Sese ega eye ega sese
Adifafun laba nile o
Imo egba ni ile alake
Nigbati oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa niki eleyin orubo kole badaja pe oju aje nip on eleyin ebo ni ko se ba laje loun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku
Eja
Abodire
Ewure
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Won dafa sekeseke nile olufon
Moya mowo ranwon
Mo lugbbin leyin kule orisa ojiyan
Moya mo wo ranwo aroni miini ke,
Semi abii arara mi ki seun ati loku
Abuke ile irami mi mi kese ni
Adi loku gbonigboni sale sale
Adifa fun oyela ti n tode orun bowaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin rubo ki ole bala ape oju aye nipon eleyin ki won osi se ifa be si kole ba lowo lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye kan
Epo
Eko
Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

A o toju ina elegede ati ose dudu ao wa gun po ao ma fi we laro laro
ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe ayure pelu ewe apada ao wa jo po mo odidi atare kan a o wa fi sin gbere mokanlelogun si ori

Videos

Watch Oyeku Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Meji Odu.