Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Oyekú Méjì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Oyekú Méjì signifies profound transformation and renewal. It suggests a powerful change in ones life.
Listen
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyesese labo loke Omo araye se bi oju mo lomon Adifafun baba yeku yeku Ti won o mope ni oyeku sapana Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje kini yio yeku nu lori awo Eji oye Ifa ni yio yeku nu lori awo Eji oye.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii orubo laiku pe ki emi re ole gun ebo ni kose dada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Epo Eko Obi Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Opa gbogbo ni siwaju agbon nini Ese mejeji ni jija de ona gborogan gborogan Ati pe obi enu bobo aso kitipa abita wele Adifa fun enlojo aso Lojo ti won tode orun bo wale aye Ebo ni won ni ki won ose Won gbe bo ni be won rubo Nje kele loru o Kele lo tu Nje aso tomebo kiyo ruu Toba toku je tan yio pada seyin Aso tomebo ki yorun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki awon omo iya meta ki won o rub o emi won ki emi won ba le gn ti won ofi aso dudu aso funfun ati aso pupa kobo ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aso dudu Aso pupa Aso funfun Eran ewure kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Atefa bere arobiunda Apaju bere airobiunko Sese ega eye ega sese Adifafun laba nile o Imo egba ni ile alake Nigbati oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni kose O gbe bo ni be orubo Nje kini yio sole doja fawo Sese ega eye ega sese Ifa ni yoo so le doja fawo ope bi Ko sai soja dile

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa niki eleyin orubo kole badaja pe oju aje nip on eleyin ebo ni ko se ba laje loun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodire Ewure Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Won dafa sekeseke nile olufon Moya mowo ranwon Mo lugbbin leyin kule orisa ojiyan Moya mo wo ranwo aroni miini ke, Semi abii arara mi ki seun ati loku Abuke ile irami mi mi kese ni Adi loku gbonigboni sale sale Adifa fun oyela ti n tode orun bowaye Ebo won ni ko se nife O sio gbebo nibe o rubo Oyela bele gede tan naa ari naa oyela kari oun re gbogbo Oyela belegede naa arinaa oyela

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin rubo ki ole bala ape oju aye nipon eleyin ki won osi se ifa be si kole ba lowo lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

A o toju ina elegede ati ose dudu ao wa gun po ao ma fi we laro laro ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe ayure pelu ewe apada ao wa jo po mo odidi atare kan a o wa fi sin gbere mokanlelogun si ori

Videos

Watch Oyekú Méjì teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyekú Méjì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì, Òyèkù Íròsùn.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyekú Méjì Odu.