Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Oturuopon ko
Awo ori lose fafun ori
Ori tode orubo waye
ao toju ewe iyeye pelu owo eyo iyere ao wa lopo ao wa fi se eran okete odidi kan lepo niyo ao wa ko obe yin si ori ifa ti obajinaa too ao wa se adurasi ao wa je obe naa gbogbo oun ti abele je ni nu obe yin ao ko si ibikan ao wa mu ewe mejejeji yin ao wa gun papo ao wa po mon ose dudu ao wa on fi we laro laro
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki elelyi orubo ola kio lobo ori
Re pelu eye etu kan kio si lo fi eye eku kan bo fa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
obi
Ese — Yoruba Verse
Adifafun orunmila ni jo ti
Baba momi oju sogbere aje
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
elelyi ki elleyi orubo ki o si lobo
ifa pelu pepeye kio si fi
oruko rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye kan
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Oturupon ka
Pon ko ponko majalawa
Adifafun omi subu laje omo
Oni gbobu aran
Igba ti momi oju sogbere omo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
elelyi pe oju omo nip on
elelyi korubo pelu eran ewure
kan ati ye imu fun ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Oti
Ese — Yoruba Verse
Ponkoponko ponran ete
Adifafun egbe aye
Abufun torun
Igba ti won tode orun bowaye
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
eleyi ki eleyi olo bo egbe
orun re pelu gogbo oun
tenu je kio si fi akuko adire meta rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Gbogbo oun ti enuja
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Oturupon Ika is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Ika Odu.
