Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òkánràn Òyèkù

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies transformation and the importance of embracing change.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/okanran-oyeku
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Yangin abori kugun Adifafun olokun Eyi tomore yenkun Ti omo re yanku loju aye re Ebo ni won ni kose Osigbe bo orubo Ero ipo Ero ofa E wa bani laiku kangiri

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pe oun pe ire aiku fun eleyi ki eleyi ofi opo lopo isu kun ebo ru pelu akuko adire meji rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Opolopo isuko Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Koko rere todara niba nigbe inu ile Eyin ti koseni awo siu eranko Adifafun osan abu foro Nijo tibaba momi Ojusogbere omo Ebo ni won ni kose Osigbebo ni be orubo Nje ela isode Ifaje kibibi osan Bi oro

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire omo fun eleyi ki lelyi ofin opolopo osan ati oro rubo kio si fi eku eja abodie rubo kio fib o ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodie Osan Oro Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Tekuti lawo omode Tekata lawo alare Ikakan soso loku kodeji oye Beni kole deji oye Adifafun sebo koru omo Igba ti n momi oju sogbere ire EBO niwon ni kose Osi gbebo nibe orubo Nje emi sebotan Aratuwaminmi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nipe oun pe ire gbogbo fun eleyi ki eleyi olo fie ran elede bo ifa ki ara ole bade

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran elede kan Epo Eko Obi Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Agbon nije nibi are are Ope agunka logarun gase Ope agunkan nidun loru Oja gbo lo Adifafun olu nijo tilolejola ifa Lode isa laye Ebo ni won ni kose Osi gebebo nibe orubo Nje moreke loja Emi osan wo Ojogbonikere ola ifa ni tuonje Ojogbo ni kere Mora oun gbogbo loja Emi osan wo ojogbo ni kere Ola ifa ni monu je

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere gbogbo fun elelyi ki elelyi orubo kio si lobo ifa pelu eran ewure kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe akika die ao fin se eyin adire ibile meta pelu ori ni epo re ao fi iyo si ao wa se adura si ao wa je ni ale

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju aparin isu ako ao wa fi odidi atare kan kun ati ewe apada ao wa jo papo ao wa fi si gbere larija eyin toba ku ao wa po mon ose dudu ao wa mon fi we larolaro

Videos

Watch Òkánràn Òyèkù teachings on our channel.

Explore Ifa

Òkánràn Òyèkù is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Òkánràn Ogbè, Òkánràn Iwòrì, Òkánràn Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òkánràn Òyèkù Odu.