Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Okanran Otura

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of strategic planning.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/okanran-otura
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran tuatuatua
Adifafun owo nijo ti lole gbe
Naamu niyawo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Onigba ilekun
Olagba ilekun
Gbongbon ileku kojekan onirun
Latari
Adifafun ati nu mon ti se omo
Bibi inu agbonmeregun
Won ni korubo ni laiku arare
Ogbebo ni be orubo
Nje orumila kon fi atunu
Man omo ni fin ku paje
Oun iku meji ati imule
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okanran tuatuatua
Babalawo enu
Losefa fun enu
Igbati be lari ota
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran tua dasase
Abi ise warawara
Adifafun orunmila ire gbogbo lo lo de
Kowo le EBO ni won ni kose
Osi gbobe ni be orubo
Nje aje loto tikode ko
Ifa owinrinwin ede loni kode
Ire gbogbo tolo ti kode
Ko ifa owinrinwin wede loni kode

Videos

Watch Okanran Otura teachings on our channel.

Explore Ifa

Okanran Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Okanran Meji, Okanran Ogbe, Okanran Oyeku, Okanran Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Okanran Otura Odu.