Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun ogbe ti o fi igo oti kan soso segun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Apajuba bieledun
Eesun nikan ronini
Adifafun orunmila
Ti won ran ajogun merin wo silere
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki orubo ifa ni awon ota po fun elelyi koruibo ko mabe eru ko
Sini oro akin lenu komo moja iya lawujo ki o se ma se etutu dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun jegbe
Tin re inu igbe lo he ire wale
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope awon omo iya meta kan wa nibe yen ki won o rubo fun awon meteta ki won o le bani laari
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku eja eyele akuko adire opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun onidiku omo amejimojo awure
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ko rubo ifa ni oun pe ire ola fun ifa ni igbo ni oore re wa komo jina sibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo efun
Opolopo osun
Opolopo owo
Eyele
Akuko adire
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe ola igba ati eyokan eso olowerenjeje igba ati eyokan odidi atare aojopo ao mo filo omigbonan tabi oti larolaro.
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
MEDICINE
Omo irula mokanla omo atara mokanla ao lo po mo arawon ao fi singbere iwori aweda si apa osi.
MEDICINE
Explore Ifa
Ogbe Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ogbe Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogbe Otura Odu.
