Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Ogbe Oturupon

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Ògbe Òtùrùpòn Excerpt
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ogbe-oturupon
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oturu pong be pongba
Alapo agbe opn gioko
Adifafun atirose
Nijo tilo oju de oba esilolejo
Ebo ni won nikose
O sigbebo nibe orubo
Nje mosebo oturupongbe pongba
Mose be oturupon gbe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere gbogbo fun
eleyi pe oun sip ere iyin fun ebo
ni kose kio si lobo ifa pelu pepeye

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye Kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Elubo lodanu monhun
Adifafun oja nijo tiraye apesin
pintinpinti
EBO ni won ni kose
osigbebo nibe orubo
nje otogege kepe simi
nitori doja
nitodeni apesin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire apesin fun eleyi kio lobo orisa pelu opolopo igbin kio si fin eku eja abodie bo ifa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan
Eja kan
Abodie kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Olorupongbe pon gba
Alapon gbepon gioko
Aluponmongbe mongbepongba
Adifafun iyalode ipo
Eyi tiyio ni ewure darandaran nile
Ebo ni won ni kose
O si gberbo nibe orubo
Nje otukoran bowa o
Ewure abenu funfun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire isegun fun eleyi
ki eleyi olo fi ewure ti enu re ba funfun bo ifa ki ogun ti ja elelyi ole bASE kiwon osi se ifa re fun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure elenu funfun kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oturupongbe pongba
Alapongbe pongioko
Adifafun alabahun
Nijo ti o le gbingba oro loko
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje igbalahun teregungun monja
Gungun tere igba olowo
Teregungun monja gungun tere igba
Elese teregungun monja
Gungun tere igba lahun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni ki elelyi orubo isegun
pe ire fun elelyi amon ogun be fun ko rubo ki o leba segun pe lu akuko adire meta kiwon omon fi okan bo esu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

akuko adire meta
epo
eko
obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ewe anu pelu ata ijosin
ao fi se odindin ijapa kan ni epo
niyo ao wa gba iyere osun tia fid a
ifayin si ao wa se adura si ao wa je obe naa.

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao loha iru ara ewure ti a fib o
Ifayin ao wa fi ewe apada si
Ao wa gun mon ose dundun
Ao wa mon fi ose naa we larolaro

Videos

Watch Ogbe Oturupon teachings on our channel.

Explore Ifa

Ogbe Oturupon is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ogbe Oturupon Odu.