Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ogbe Irosun

Ogbe Irosun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Ogbe Irosun signifies spiritual victory, perseverance, and the importance of sacrifice to achieve success and protection.
Listen
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ogbe-irosun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ogbe dawosun tele

Tio moje larin osika

Ebo won ni o se

Osi gbebo won ni o se

Osi gbe ebo nibe o rubo

Nje asemo enirere laape

Awonhon a semo

Awon osika laape eyin.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni to da ifayi ifa ni kioruno ko le ba segun ota ifa ni arin ota lelelyi wa ifa ni korubo kola bayori ju won lo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko

Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Eroyaa eroya

Adifafun laawon

Omo ako iruke meji sodun

Nitori ire

Ebo won ni o se

Osi gbebo nibe o rubo

Nje eero yaa o eroya eroya wa

E wa wo ikin awa

Eroyawa e wa w oni fa.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifapere fun eni toda ogbe rosun ki elelyi o rubo kola badi eni apesin ko si iruke rubo pelu aso funfun ifape okiki re okan kari agbanla aye kosi ma se odun fun ifa dada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji

Asofunfun opameta

Iruke meji

Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Opa gbogbo ori ewure ayere yere ake

Adifafun orunmila

Won ni ki baba o mo garun wo ola ololamo

Ebo won ni o se

O si gbebo orubo

Nje ola ifa otan o

Ola ifa kuleyin

Ola awo rere koleerun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifa yi ifa ni ojuire ni ponm elleyi ko rubo ifa si ni o ganrun won awon to ti ni owo ifani korubo pe oun naa yoni owo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele

Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ogbe dawosun tele o

Mororo loju opon

Adifafun ega sese ti se omo olukere eye

Ebo won ni ose

Osi gbebo nibe orubo

Nje, ega loru egalo tu

Ega lorubo apesin.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi korubo kole badi eni apesin ifa ni ko fi gbeboadie pelu eku eja obi oti bofa ko le badieni apesin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abooadie

Eku

Eja

Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe saworopepe ewe ekuya ewe ogbo imirun aogun pomo ose dudu ao ma fiwe larolaro

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ewe oojo (ewedu) ao jo po mo odidi atara kan ao ma fifo eko tutut mu laro laro.

Videos

Watch Ogbe Irosun teachings on our channel.

Explore Ifa

Ogbe Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Owonrin.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ogbe Irosun Odu.