Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ogbe Iwori

Ogbe Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
Ogbe Iwori also teaches the importance of not lending what you cannot part with, as the borrower may be unwilling to return it.
Listen
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ogbe-iwori
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Lala toroke ile nibo
Adifafun efufu lele
Ti o ni oun o mun oun
Ile je gbe
Ebo ni won ni ki ile ose
Osi gbebo nibe orubo
Nje efufu lele oni mun
Oun ile je gbe lailai

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire fun eleyii, pe ki eleyii orubo ki aye mon ba gba eto re lowo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji
Akuko adire meji
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni iwori bobobo
Babalawo ekolo
Adifafun ekolo
Ngbati nlo isale abata
Nitori omo
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Ekolo ni oun ti sebo
Iwori bobobo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyii orubo
Ntori omo ko le badi
Olomo laye

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abo adie meji
Eyele funfun meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ona gburugburu gburu
Ejeka to wo bi aba
Ri ire nibe
Adifafun iwori ti nlole ree ko ire ba ogbe egbon nile
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje iwori wo ni
Iwori tolo ko ire ba
Ogbe nile ni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki omo iya meji orubo ki won o le ko ire dele lati irin ajo Ki enikan osi mon soroju
Ki won o si mon ja arawon niyan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji
Agbeboadie meji
Epo at eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ao toju ewe ajilekese ti o po dada egbo feru ao gun mon ose dudud aote iyere osun ni iwori bogbe
Ao se adure si ao mon fi we lori okuta ako ni ojo ketaketa
Igbin to pinu merin, ewe sajeje topo ewe adurosusu, ao lo pelu iyere ao fi se igbin yen lepo niyo je, ao te iyere osun ni oduifa iwori bogbe ao je ti abafe sun lale.

Videos

Watch Ogbe Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Ogbe Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Odi, Ogbe Irosun, Ogbe Owonrin.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ogbe Iwori Odu.