Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Ògbe Òfún

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Ògbe Òfún
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ogbe-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofun nangbe nanra Aja nara pati pati Adifa fun gudu gudu Tii selegbe dundun Igba tin be laarin ota Ebo won ni o se O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E banin laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo nitori wipe aarin ota lowa Kosi fi obi meji bori omore Ori omo eleyi nin yio ba segun Paapaaju lo ibikan leleyin loyi Korubo kolebaa de Kiwon oman pa soun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Akuko kan
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofun nangbe nanra Aja nanra pati pati Adifa feetan ti n se elegbe eyin Igba tinbe laarin ota Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Omo enin lelegbe eni Eetan ni n selegbe eyin Omo eni lelegbe eni

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo Kosifi agbon bori omore Ati eetan eyin Nintori ki awon ota Oman baa man pa omo eleyi Nintori won ofe keleyi Oloman laye Wonfe pa omo re tan Pata pata nin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun nangbe nanra Aja nanra pati pati Adifafun lewa Ti n tode orun bo waye Ebo wo ni o se O gbebo nibe o rubo Nje owo lewa oun omo Aise fuja lailowo lowo Ile lewa oun omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo Ire aje lopo lopo fun eleyi Keleyi osi bo eegun Eegun yio dako owo re wafun Eleyi yio si kole lodun yi Nintori lati ode orun leleyi tiyan ri ola Kosinin eegun ti man bo lodo dun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Aofi eko oole obi oti, ati owo bo eegun
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun nangbe nanra Aja nanra pati pati Aigun okan agba gudu gudu eeso jogba dundun Adifafun orunmila Baba ji baba orowo kan a yona Ebo won ni o se Orunmila si gbebo nibe orubo Kee pe Kee jinna Aje wa je de tuturu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifaninkeleyi Orubo nintori oju aye Npan eleyi eleyi ko lowo lowo Eleyi saro ye owo Korubo irere feede tan Keleyi osiman sooto

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

IFA OFUN NANGBE Eekan gudu gudu awo ilu dundun eetan eyin adidi atare kan aojo po ao man fi foko mun aotun fi sin gere meta meta nindeti Awon oju eegun Ewe je oojo Ewe saworo pepe oojo Alupaide oojo Ao gun gbogbo re po mose Ao man fiwe

Videos

Watch Ògbe Òfún teachings on our channel.

Explore Ifa

Ògbe Òfún is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ògbe Òfún Odu.