O
Ògbe Òdì warns against restlessness and stresses the importance of sacrifice for achieving success and stability for whom this odu appeared for in Ifa Divination.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Yereyere moko moko
Moko yereyere
Adifafun ekite eyitio ji ade oba gbe
Ebo won ni ose
Osi gbe ebo ni be orubo
Nje yereyere moko moko
Moko yereyere
Mojade oba gbe.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni to da ifa yi ifa ni ki eleyi o rubo atimo pe awon kan o tiran mo leleyi pe aji inkan awon gbe koso ope oun lounji ire nbe leyinre ifa sin ire wa fun nipa se eniyan.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Seerebepe
Adifafun olomun
Ti won ni korubo atimo
Gbebo orubo ogberu otu
Nje seerebepo olomun lojale
Seerebeope ojale
Ogbe emon seerebepe
Olomun lojoye
Ojoye odade seerebepe
Eroyaa eroya
Adifafun laawon
Omo ako iruke meji sodun
Nitori ire
Ebo won ni o se
Osi gbebo nibe o rubo
Nje eero yaa o eroya eroya wa
E wa wo ikin awa
Eroyawa e wa w oni fa.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ifani ire oye bowa fun kosi rubo atimo kio simolo oja fun ojo meje ifa ni ti won ba fi oye lo ko mo ko yo fi ekunmeji rubo ko gbodo lora funrare Koran eniyan loni o.
Ifapere fun eni toda ogbe rosun ki elelyi o rubo kola badi eni apesin ko si iruke rubo pelu aso funfun ifape okiki re okan kari agbanla aye kosi ma se odun fun ifa dada.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Akuko
Eyele
Opolopo owo.
Eyele meji
Asofunfun opameta
Iruke meji
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Agbo o koja beni abe o kori
Adifafun amo o ti won o ma wo tikutiku
Ebo ni won ni kose
Osi gbebonibe orubo
Nje ko kumo omowo amoo kumo
Olodi moyo
Agbo o koja beni abe o kori.
Opa gbogbo ori ewure ayere yere ake
Adifafun orunmila
Won ni ki baba o mo garun wo ola ololamo
Ebo won ni o se
O si gbebo orubo
Nje ola ifa otan o
Ola ifa kuleyin
Ola awo rere koleerun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire fun eni to ifayi ifa ni awon kan wobi koti ku korujkbo ifa ni koniku ifa ni ko fi opolopo abee fele kun ebore ko si fi aboadie bofa ati eku eja obi.
Ifa pere fun eni toda ifa yi ifa ni ojuire ni ponm elleyi ko rubo ifa si ni o ganrun won awon to ti ni owo ifani korubo pe oun naa yoni owo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku,
Eja agbeboadie
Abee
Opolopo owo.
Eyele
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Kolalu lawo abe ota
Ejo nio ko nangbon nangbon wosa
Adi fafun baayanni ti se aworo de isele
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje eero sele nbo lona
Dada bunmi lookan kin so mori
Ogbe dawosun tele o
Mororo loju opon
Adifafun ega sese ti se omo olukere eye
Ebo won ni ose
Osi gbebo nibe orubo
Nje, ega loru egalo tu
Ega lorubo apesin.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ika pere fun eni to ba ifayi ifa ni korubo ki ire okere ko leto lowo ko fi owo wyo ti koleju ku ebo kosi bo baayan ni.
Ifa pere fun eni toda ifayi korubo kole badi eni apesin ifa ni ko fi gbeboadie pelu eku eja obi oti bofa ko le badieni apesin
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo eyo
Opolopo owo
Abooadie
Eku
Eja
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe saworopepe eru Alamo ao gun pomo ose dudu ao ko sinu ike funfun ao ma fiwe pelu kankauinkan tutu.
Ewe saworopepe ewe ekuya ewe ogbo imirun aogun pomo ose dudu ao ma fiwe larolaro
MEDICINE
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe rinrin ewe tete abalaya epo ogede omini odid atare kan aojo po mo arawon ao fi sin gbere ogun ati eyokan si arin ori (21)
Ewe oojo (ewedu) ao jo po mo odidi atara kan ao ma fifo eko tutut mu laro laro.
MEDICINE
Explore Ifa
Ogbe Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Irosun, Ogbe Owonrin.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogbe Odi Odu.
