O
Ogbe Obara, also known as Ogbe Bara emphasizes the importance of sacrifice in averting illness and enhancing well-being.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Openopelejape
Penpelejape adie opipi yemoniwon korapabo
Eyin koriye bodie
Adifafun onipele omo aradie sipile ola
Igba tin momioju sogbere ire
Ebo won ni ko se
Osi gbebo nibe orubo
Kepe
Kejina
Ewa bani nije butu ire
Opeje butu ire labani lese oba orisa
OGBE KANRAN
Agbodo elubo ni sodo gbankogba ko
Adifafun abogunde
Tiwon o mun joye oba ewilado
Ebo won ni o se
Osi gbebo nibe o rubo
Nje enikan ogbon o
Enikan o moran
Amo pabo gunde le joba
Abogunde joba ewi lado
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ifapereola ifani eleyi ola korubo ko fi opolopo adie rubo ko sima sin edie
Ifa pere oye fun eni toda ifayi ati ire ola korubo ki awon ire wonyi ola ba to lowos
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko eyele adie pipo opolopo owo
Eyele akuko opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Opopo ara orun osukun
Abimo laye anyo sese
Hinso sinsoko jomo inaja onirun lori
Adifafun keere tise obinrin
Bata igba tin fomioju sogbere omo
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje keere momo de obinrin abata
Hin babimobire ni bayo.
Ogbe ki kanran komo se
Adifafun asofunfun tise wolewode orisa
Igba tin momi oju sogbere ire
Ebo won ni o se
Osi gbe nibe o rubo
Keepe
Keejina
E wa ba ni nije butu ire
Ope jebutu ire la ba ni lese oba orisa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere omo fun eni todayi ifa pe oju omo ni pon elelyi ko rubo yosi di olomo laye ko fi eku eja aboadie bofa.
Ifa pere fun eni toda ogbe kanra ki elleyi o rubo ki ire ole bato lowo kio sibo orisanla ifa ni irawo eleyi o tan kariaye
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Obi
Oti
Aboadie
Opolopo owo
Igbin eyele opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Opoile abuinu keredudud keredu du
Adifafun ogbe tin lo le bo ikinre ni gbara ode de Ebo won ni ose
Osi gbebo nibe o rubo
Kepe
Kejina
E wa bani nije butu ire ope,
Jebutu ire laba ni lese oba orisa.
Ogbe kikanra komose
Adifafun ogbe tinlole kan eboremole lodo esu odara Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje ogbelo kan ku ogbelokan
Arun ogbe lomun gbogbo ajogun kanmole
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa fore gbogbo fun eleyii pe, ebo ni ko ru, yoo nire gbogbo, ko si maa bo ikin re daa daa.
Ifa pere fun eni to da ogbe kanran ifa ni ki elleyi o rubo ni tori iku ebo to ba si niyi won o kan mo le ni di esu ni o
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Oti
Opolopo owo
Akuko opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ogbe bara bara lageti
Sonso orire nio logun
Adifafun agberi oga omo akan nin gbongbon mko yun
Igba tin raye alainku
Ebo won ni o se
Osi gbebo nibe orubo
Nje won pe agberi lorun ko wa mo
Aso funfun ni fi ransesi won
Abi febo tilekun orun gbongbon.
Ogbe kikan komo se
Adifafun orunmila won ranse ikupe baba laye
Won ranse iku pe babalala de orun
Ebo won ni kose
Osi gbebo ni be orubo
Ruru ebo
Eru atuka esu
Ewa bani laiku kangiri
Ope aiku kangiri labani lese oba orisa
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo ifani ounpere aiku funfun ifa ni eleyi koni bawon jepe olorun kofi asofun ati pupo rubo
Ifa pe ire fun eni toda ifayi ki elleyi o rubo nitori iku ifani oun konije ki elleyi o bawonje ipe olorun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko asopupa asofunfun opolopo owo
Akuko opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ori ahun kan isu emina alubosa elewe egbo wowo etu ibon gidi ao gun po mo ose ao ko sinu isa suntutu ao ma fiwe laro laro
Ewe akisan ewe sajeje eyele funfun kan ao gun pomo ose ao ko sinu fitila oloju meta ao ma fi we.
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Opolopo ikarahun igbin aojo po mo odidfi atare kan ao fisin gbere meta si arin ori
MEDICINE
Ase ale ase aro igi iroko aopa ao jo pa mo odidid atare kan ao ma fi lo eko tutu laro laro
Explore Ifa
Ogbe Obara is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ogbe Obara Odu.
